Lyrics Oloore - 9ice
                                                Olóore 
                                                màmá 
                                                o, 
                                                olóore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                olóore
 
                                    
                                
                                                Olóore
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                to 
                                                    ń 
                                                ṣáyé 
                                                fún 
                                                mí 
                                                pọjù 
                                                báyìí 
                                                lọ
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                to 
                                                    ń 
                                                ṣáyé 
                                                fún 
                                                mí 
                                                pọjù 
                                                bẹ 
                                                ṣe 
                                                ro, 
                                                wo-woo
 
                                    
                                
                                                Olóore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                olóore 
                                                màmá 
                                                o
 
                                    
                                
                                                Ore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                ore 
                                                màmá 
                                                o, 
                                                olóore
 
                                    
                                
                                                Tẹnì-tẹnì 
                                                àpá 
                                                lára, 
                                                igunpá 
                                                níye 
                                                kàn
 
                                    
                                
                                                Jọwọ, 
                                                kọ 
                                                má 
                                                sọ
 
                                    
                                
                                                Eh, 
                                                tẹnì-tẹnì 
                                                àpá 
                                                lára, 
                                                igunpá 
                                                níye 
                                                kàn
 
                                    
                                
                                                Jọwọ, 
                                                kọ 
                                                má 
                                                sọọ́
 
                                    
                                
                                                Mo 
                                                gbójú 
                                                mí 
                                                sókè, 
                                                níbo 
                                                ìrànlọ́wọ́ 
                                                yí 
                                                    ò 
                                                tí 
                                                wá?
 
                                    
                                
                                                Má 
                                                k'Adeunga, 
                                                Bàbá 
                                                ṣe 
                                                ránwọ, 
                                                àá 
                                                témi 
                                                    á 
                                                kùn, 
                                                lakun 
                                                wọ 
                                                sílẹ, 
                                                ee
 
                                    
                                
                                                Ilé 
                                                ní 
                                                mo 
                                                wa 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí, 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí
 
                                    
                                
                                                Ilé 
                                                ní 
                                                mo 
                                                wa 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí, 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí
 
                                    
                                
                                                Wọn 
                                                ní 
                                                Adeunga 
                                                    ń 
                                                pé 
                                                mí, 
                                                ìṣó 
                                                lodé
 
                                    
                                
                                                Olóore 
                                                kore 
                                                wá, 
                                                ki 
                                                    ń 
                                                wa 
                                                gba're 
                                                owó 
                                                ee
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                tọ 
                                                    ń 
                                                ṣáyé 
                                                fún 
                                                mí 
                                                pọju 
                                                báyìí 
                                                lọ
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                tọ 
                                                    ń 
                                                ṣáyé 
                                                fún 
                                                mí 
                                                pọjù 
                                                bẹ 
                                                ṣe 
                                                ro, 
                                                wo-woo
 
                                    
                                
                                                Olóore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                olóore 
                                                màmá 
                                                o
 
                                    
                                
                                                Ore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                ore 
                                                màmá, 
                                                olóore
 
                                    
                                
                                                Many 
                                                reason, 
                                                every 
                                                other 
                                                day 
                                                ní 
                                                má 
                                                fí 
                                                dúpẹ
 
                                    
                                
                                                Many 
                                                reason, 
                                                every 
                                                other 
                                                day 
                                                ní 
                                                má 
                                                fí 
                                                dúpẹ
 
                                    
                                
                                                Lọwọ 
                                                Toyin 
                                                Kọlade, 
                                                Toyin 
                                                Kọlade
 
                                    
                                
                                                Àyà 
                                                Price 
                                                Káyọ̀dé 
                                                Kọlade, 
                                                Iléṣà 
                                                ṣá 
                                                nílé
 
                                    
                                
                                                Ìyá 
                                                l'Ọjà 
                                                Odùduwà, 
                                                Naija 
                                                Federal
 
                                    
                                
                                                Màmá, 
                                                mo 
                                                kìí 
                                                ẹ, 
                                                ẹ-ẹ, 
                                                olóore
 
                                    
                                
                                                Ilé 
                                                ní 
                                                mo 
                                                wa 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí, 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí
 
                                    
                                
                                                Ilé 
                                                ní 
                                                mo 
                                                wa 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí, 
                                                tọ 
                                                tá 
                                                mí 
                                                jí
 
                                    
                                
                                                Toyin 
                                                Kọlade 
                                                pé 
                                                mí 
                                                o
 
                                    
                                
                                                    E 
                                                ro 
                                                wa 
                                                wo 
                                                mí 
                                                lóde, 
                                                    e 
                                                ro 
                                                wá 
                                                wo 
                                                owó 
                                                tí 
                                                mo 
                                                gbà 
                                                o
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                tọ 
                                                    ń 
                                                ṣáyé 
                                                fún 
                                                mí 
                                                pọjù 
                                                báyìí 
                                                lọ
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                tọ 
                                                    ń 
                                                ṣáyé 
                                                fún 
                                                mí 
                                                pọjù 
                                                bẹ 
                                                ṣe 
                                                ro, 
                                                wo-woo
 
                                    
                                
                                                Olóore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                olóore 
                                                màmá 
                                                o
 
                                    
                                
                                                Ore 
                                                bàbá 
                                                o, 
                                                ore 
                                                màmá, 
                                                olóore
 
                                    
                                
                                                Many 
                                                reason, 
                                                every 
                                                other 
                                                day 
                                                ní 
                                                má 
                                                fí 
                                                dúpẹ
 
                                    
                                
                                                Many 
                                                reason, 
                                                every 
                                                other 
                                                day 
                                                ní 
                                                má 
                                                fí 
                                                dúpẹ
 
                                    
                                
                                                Lọwọ 
                                                àwọn 
                                                olóore 
                                                mí, 
                                                Owó 
                                                Debọ
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                olóore, 
                                                Dayọ 
                                                Iwo
 
                                    
                                
                                                Àwọn 
                                                olóore 
                                                mí 
                                                (Ṣina 
                                                Olu 
                                                MT)
 
                                    
                                
                                                Teepay, 
                                                ìwọ 
                                                olóore 
                                                mí
 
                                    
                                
                                                Tiamo, 
                                                Tiyabo, 
                                                Tiamo, 
                                                iwọ 
                                                olóore
 
                                    
                                
                                                Ọmọjuwa, 
                                                àwọn 
                                                olóore 
                                                míì
 
                                    
                                
                                                (It's 
                                                Bizzle 
                                                on 
                                                the 
                                                mix)
 
                                    
                                 
                            1 Iba
2 Murebo
3 Otami
4 I Cancel
5 Power Must Change Hands
6 Olorun Loni Kori Be E
7 Gbare Gbare
8 Iwaju
9 Oloore
10 Aranbada
Attention! Feel free to leave feedback.
                 
                                                         
                                                         
                                                         
                                                         
                                                        