9ice - Ojo Lyrics

Lyrics Ojo - 9ice



Ojo t'oro s'ewuro lo ro s'ireke
Sebi Sathiramoni baba nba wa se
Ase show ni Abidjan a tun se ni malay
Koriko t'erin bate ko ma tun dide
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Ema je njabo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Ema je njabo
Omo t'oba sise dede oye koni igbadun
Adun obe o nbe ninu ishasun
This one na the part one you never see the part two ooo We are relevant just like your car key
Won ni mo sare wa mo sare wa
Mo detun gbe eni wa mo gbe eni wa
Mo de pe salawa pe salewa
Ko de lo gbe oti wa gbe oti wa
Ojo t'oro s'ewuro lo ro s'ireke
Sebi Sathiramoni baba nba wa se
Ase show ni Abidjan a tun se ni malay
Koriko t'erin bate ko ma tun dide
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Ema je njabo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Ema je njabo
Ise ni eiye ile se ko to fi sese ko'le
Ise ni okababa se to fi poporo sho ile
Ise nla ni mo se ki to pa owo mi wale
Ma jaiye ori mi ma fi amebo mi sho ile
Won ni mo sare wa mo sare wa
Mo detun gbe eni wa mo gbe eni wa
Mo de pe salawa pe salewa
Ko de lo gbe oti wa gbe oti wa
Ojo t'oro s'ewuro lo ro s'ireke
Sebi Sathiramoni baba nba wa se
Ase show ni Abidjan a tun se ni malay
Koriko t'erin bate ko ma tun dide
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Ema je njabo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo
Oke agba ni mo gun yii oo Ema je njabo
Khoded oke
Khoded oke
Khoded Khoded Khoded ema je njabo




9ice - Id Cabasa
Album Id Cabasa
date of release
20-11-2016




Attention! Feel free to leave feedback.