Kenny Kore - Bebelube Lyrics

Lyrics Bebelube - Kenny Kore



Wa sinmi ko ni gbo
Bi o ba ja ko ni gba
Omo akin you're too bold
You're too bold
I'm indulging you no more
Bo ba fesi ma fa e leti
Omo ode you're too cold
You're too cold
Omo to ni iya oun o le be
Pe baba oun o le be
Se oun naa ti bebelube?
Omo to ni iya oun o le be
Pe baba oun o le be
Se oun naa ti bebelube?
(Abi oun naa ti bebelube?)
Oun naa ti bebelube
(Jan ja ja du bi du du)
Oun naa ti bebelube
(Se oun naa ti bebelube?)
Oun naa ti bebelube
Oun naa ti bebelube
Bomo laso bi agba
Ko le lakisa bi agba
(You hear?)
Ohun toju arugbo ri lo je o ko wo nu
(You hear?)
You with your philosophy might need to take a cue from me
Respect, connect, protect and don't reject ewu ori
O, je o wu e lori
Pe oro agba ma ye iba
Ooooo
Omo to ni iya oun o le be
Pe baba oun o le be
Se oun naa ti bebelube?
Omo to ni iya oun o le be
Pe baba oun o le be
Se oun naa ti bebelube?
(Abi oun naa ti bebelube o?)
Oun naa ti bebelube
(Se oun naa ti bebelube?)
Oun naa ti bebelube
(Abi oun naa ti bebelube o?)
Oun naa ti bebelube
(Se oun naa ti bebelube?)
Oun naa ti bebelube
Don't let the darkness inside you
Keep you from coming home
Don't let the darkness inside you
Keep you from coming home to me omo mi
Oooo
Omo to ni iya oun o le be
Pe baba oun o le be
Se oun naa ti bebelube?
Omo to ni iya oun o le be
Pe baba oun o le be
Se oun naa ti bebelube?
(Abi oun naa ti bebelube o?)
Oun naa ti bebelube
(Se oun naa ti bebelube?)
Oun naa ti bebelube
(Abi oun naa ti bebelube?)
(Ma je o ti)
Oun naa ti bebelube
(Se oun naa ti bebelube?)
(Ma je o sa)
Oun naa ti bebelube
Ma je o sonu momi lowo
(Tongues)
Se oun naa ti...?
Se oun naa ti bebeto?
Se oun naa ti gbe gbagi?
Se oun naa ti gbeeeee?



Writer(s): kenny kore


Kenny Kore - Eledumare classic
Album Eledumare classic
date of release
28-05-2013




Attention! Feel free to leave feedback.