Mike Abdul - Fuji Christmas Lyrics

Lyrics Fuji Christmas - Mike Abdul

Keresimesiii, odun ti de ooh (keresimesi ooh)
Odun ayo, odun ire, ire wole (keresimesi ooh)
Oni kaluku parapo, ka mope wa ooh (keresimesi ooh)
Ka je resi, je moimoi, pelu sicken (keresimesi ooh)
(HOOK)
Oya ooh, (O ya)
E fi jo tele be (O ya)
Pelu erin muse muse (O ya)
E se opo odun S'emi eeh ooh (O ya)
Igba ladun to n'egba to dara gaan (keresimesi ooh)
Keresimesi, odun yii o ni ye (keresimesi ooh)
(VERSE - 1)
Silent night, holy night; lale ojo sii
Mo gbo pe won se siha loke
Akorede ti de; maa bo, maa bo, maa bo, m'ori apere wa ooh
Ita torin de ni to de l'adun bere ooh
Eeh o beree ooh, keresimesi ooh
Te ba ti de bii to nti sele ooh, ke y'owo siibi
E fun mi ni iresi, e fun mi ni turkey, e fun mi ni omi tutu ooh
Mo fe wo Shitta ooh kerere
(CHORUS)
Keresimesiii, odun ti de ooh (keresimesi ooh)
Odun ayo, odun ire, ire wole (keresimesi ooh)
Oni kaluku parapo, ka mope wa ooh (keresimesi ooh)
Ka je resi, je moimoi, pelu sicken (keresimesi ooh)

Writer(s): Michael Olayinka Abdul

Mike Abdul - Fuji Christmas
Album Fuji Christmas
date of release
08-12-2016

Attention! Feel free to leave feedback.