Teni feat. Fridayy - Malaika x Fridayy Lyrics

Lyrics Malaika x Fridayy - Teni , Fridayy



Yo ti ma lo
Mo l'Oluwa
Bo ti le-le ju, orukọ rẹ
Eli Elijah
Eli Elijah, ah-ah
Ọrun ṣilẹkun, Malaika sọkalẹ wa
Eli Elijah o
Eli Elijah (eh-eh, eh)
Eli Elijah ah-ah (eh-eh, eh)
Ọrun ṣibolẹ, Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Ooh-ooh-ooh-ooh
Thank You for all the things You've done, hm
Could never forget where you brought me from
Jah I was weak, You made me strong, hm
I stay with You 'cause that's where I belong
And when they gang up against me, I know that You're with me
They throw dirt on my name, but You wash me, You cleanse me
You give me light in the dark as I walk through the valley
Lord, You got my soul, Lord, You got my soul
We sing, "No weapon fashioned against me shall prosper"
Back to sender (back to sender o), back to sender (mo ni, "Back to sender o") Eli, Eli
Eli Elijah (Eli Elijah)
Eli Elijah ah-ah
Ọrun ṣilẹkun (Ọrun ṣilẹkun), Malaika sọkalẹ wa
Eli Elijah ah-ah
Eli Elijah (Eli Eli)
Eli Elijah ah-ah (Eli Elijah)
Ọrun ṣibolẹ, Malaika sọkalẹ wa
Ogo ni, ogo ni, ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Ọmọ, ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Ọlọrun Ẹmi-Mimọ
Ogo ni, ogo ni, ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Ọmọ, ogo ni, ogo ni
Ogo ni fun Ọlọrun Ẹmi Mimọ
Thank You for the things that You got me through
Na only me and You
I dey cry for night, You dey wipe my eyes
Na You dey give me grace o
You say make I get faith o
Make my faith no deflate o
Don't jump from my plate o
People change, but You remain the same o
Aimọye eeyan to n ku lojoojumọ
Mi o fi yọ wọn, mo n fi dupẹ ni
Ẹru n dupẹ ni, mo fi n dupẹ ni o
Eli Elijah (eh-eh, eh)
Eli Elijah ah-ah (eh-eh, eh)
Ọrun ṣilẹkun, Malaika sọkalẹ wa
Eli Elijah o
Eli Elijah (Eli Elijah)
Eli Elijah ah-ah (oh, ooh)
Orun ṣibolẹ, Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)



Writer(s): Francis Leblanc, Oluwademilade Ayobamidele T.a Alabi, Teni Apata


Teni feat. Fridayy - Malaika x Fridayy - Single
Album Malaika x Fridayy - Single
date of release
11-10-2024



Attention! Feel free to leave feedback.