Tope Alabi - Kape Laye Lyrics

Lyrics Kape Laye - Tope Alabi



Kaape laye
Ka lo Ile aye titi
Ko ni Kaye gbo ooooooo
Aye lole lo niyan keee gbo
Igba ta gbe laye
Ohun a gbe Ile aye she gbogbo
Keledua je kaa le pitan rere
Omi aye to ru siwa seyin o
Awon kan gbaye
Won pitan iṣẹ titi
Wọn pitan ìṣòro kolopin rárá
Ọrọ wọn o Papa jasayo o'mase
O'jojo aye ni won fojú sògbérè ẹkun
Titi ikú fi p'awọn won o lenu dupẹ
Omi aye to ru siwa seyin ooo
Awọn kan gb'ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t'oda ayé
Ọrọ' ayé bo wọn lójú jọjọ alumoni
Wọn l'ayé wọn f'ogo rẹ fún satani nii
Igbagbe ṣewọn òun gbogbo tọwọ asèdá wa o'mase o'mase
Òun gbogbo toni kaluku wọn fi fesu



Writer(s): Patricia Temitope Alabi


Tope Alabi - Alagbara
Album Alagbara
date of release
17-08-2012




Attention! Feel free to leave feedback.