Lyrics Oluwa Otobi - Tope Alabi
Oluwa
o
tobi,
O
tobi
o,
O
tobi
Ko
s'eni
t'a
le
fi
s'afiwe
Re
o,
O
tobi
Ko
s'eda
t'a
le
fi
s'akawe
Re
o,
O
tobi
Oluwa
Oluwa
o
tobi,
O
tobi
o,
O
tobi
Ko
s'eni
t'a
le
fi
s'afiwe
Re
o,
O
tobi
Ko
s'eda
t'a
le
fi
s'akawe
Re
o,
O
tobi
Oluwa
O
tobi
o,
Oluwa
giga
lorile
ede
gbogbo
Gbigbega
ni
O,
Iwo
lo
logo
ni
orun
Pupopupo
ni
O,
O
koja
omi
okun
at'osa,
O
ga
po
Ajulo
O
o
se
julo
Oluwa
o
tobi,
O
tobi
o,
O
tobi
Ko
s'eni
t'a
le
fi
s'afiwe
Re
o,
O
tobi
Ko
s'eda
t'a
le
fi
s'akawe
Re
o,
O
tobi
Oluwa
Oba
lori
aye,
O
tobi
o
eh
Agba'ni
loko
eru,
Olominira
to
n
de'ni
lorun
O
fi
titobi
gba
mi
lowo
ogun
t'apa
obi
mi
o
ka
Olugbeja
mi
to
ba
mi
r'ogun
lai
mu
mi
lo
t'o
segun
Akoni
ni
O
o
Oluwa
o
tobi,
O
tobi
o,
O
tobi
Ko
s'eni
t'a
le
fi
s'afiwe
Re
o,
O
tobi
Ko
s'eda
t'a
le
fi
s'akawe
Re
o,
O
tobi
Oluwa
B'O
ti
tobi
to
oo,
laanu
Re
tobi
B'O
ti
tobi
se
o,
ododo
Re
tobi
o
O
tobi
tife
tife,
Oni
majemu
ti
kii
ye
Aro
nla
to
gbo
jije
mimu
aye
gbogbo
alai
le
tan
Ogbon
to
koja
ori
aye
gbogbo
ooo
Oluwa
o
tobi,
O
tobi
o,
O
tobi
Ko
s'eni
t'a
le
fi
s'afiwe
Re
o,
O
tobi
Ko
s'eda
t'a
le
fi
s'akawe
Re
o,
O
tobi
Oluwa
Akoko
O
tobi,
O
tobi
o
Oluwa
Ipilese
ogborin
o
yeye
O
tobi
Ibere
Eni
to
f'ogbon
da
ohun
gbogbo
Oluwa
Igbeyin
ola
nla,
o
la
la
oo
O
tobi
Opin
aye
a'torun
ko
si
'ru
Re
Oluwa
O
tobi,
O
o
se
s'akawe
lailai
o
O
tobi
Agbaagba
merinlelogun
nki
O,
O
tobi
Oluwa
Awon
angeli
won
n
ki
O,
O
tobi
O
tobi
Olorun
Elijah
Ireti
Ajanaku
Oluwa
O
ma
tobi
laye
mi,
O
tobi
ooo
O
tobi
Iwo
lo
gb'orin
t'O
o
ga,
t'O
gun,
t'O
tun
fe
Oluwa
O
ga,
O
gun,
O
fe,
O
jin,
O
tobi
la
la
O
tobi
Attention! Feel free to leave feedback.