Tope Alabi - Olorun Ni Yio Ma Je Lyrics

Lyrics Olorun Ni Yio Ma Je - Tope Alabi



Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je (Olorun ni yio ma je)
Olorun ni yio ma je (titi lai, titi lai, titi lai, titi lai)
Lana loni lola o (Lana o),
Titi de ayeraye (Loni o)
Olorun ni yio ma je (Titi Aye... Titi Aye)
Alagbara ni ko se segun o
Ipa nla ni ko de le ku ooo
Aileyipada to la ye ni ikawo
Emi se′ba oluda orun o
(Emi se'ba oluda orun)
Olorun ni yio ma je (akoko nda olu nda aye)
Olorun ni yio ma je (patapata pira ogo nibi to pari si)
Lana loni lola o (patapata ola)
Titi de ayeraye
Olorun ni yio maje
Ailetuwa o ti wa ko to da orun
Tale ri ni ati titi loni
Eni ni igba ti o ni bere
Beni ko lopin
Mo juba akoda aye o
(Patapata ogo)
Olorun ni yio maje
(Eni lade to ti dade ka to d′aye)
Olorun ni yio ma je
(Eni lade to ti dade ka to da orun)
Lana loni lola o (Isaju Aye)
Titi de ayeraye (Isaju Orun)
Olorun ni yio ma je
Ko seni to da nigba toti njoba o
A o towo eda kan hun ade ori e
Akobi orun o
Olusa ju aiye de
Jehova emi se ba o (okankan oju awon agba lorun)
Olorun ni yio ma je (iriju oju awon angeli ojojumo)
Olorun ni yio ma je (iba eni ta won t'orun se ti won o dake)
Kosi ariyan jiyan lori gun merin orun ati aye
Ko ni sai je olorun mo
Eeeeh
Olorun ni yio ma je (iwo ni kan lo ma je olorun titi)
Olorun ni yio ma je (oti je olorun ko to da orun rara)
Ko si ariyan jiyan lori gun merin orun ati aye o
Ko ni sai je olorun mo (Iba o iba o)
Olorun ni yio ma je (emi seba oro kodo asiri aye)
Olorun ni yio ma je(asiri aye pelu orun, owo re ni kan lowa)
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je (akoko ati eyin)



Writer(s): Patricia Temitope Alabi


Tope Alabi - Yes and Amen
Album Yes and Amen
date of release
18-03-2018




Attention! Feel free to leave feedback.