paroles de chanson Yoruba Hymns - Oluwalonibisi
E
je
k'a
f'inu
didun
Yin
Oluwa
olore
Anu
Re
yio
wa
ti
L'ododo
daaju
daaju
On
nipa
agbara
Re
F'imole
s'aiye
titun
(E
je
ka
jo
ko)
E
je
k'a
f'inu
didun(K'a
f'inu
didun
yin
Oluwa)
Yin
Oluwa
olore(A
gba
'ni,
a
ji
'ni,
a
la
'ni,
a
gba
'ni)
Anu
Re
yio
wa
ti
(Alaanu
to
po)
L'ododo
daaju
daaju
E
yo
ninu
Oluwa,
e
yo
Eyin
t'okan
re
se
dede
Eyin
to
ti
yan
Oluwa
Le
'banuje
at'aro
lo(E
ba
mi
yo
o)
E
yo!(Ninu
Oluwa)
E
yo!(E
maa
yo
titi
aye)
Eyo
n'nu
Oluwa
e
yo!
E
yo!
E
yo!(Ayo
da?)
Eyo
n'nu
Oluwa
e
yo!
(E
gbo
naa)'Gba
t'a
ba
nja
ija
rere
Ti
ota
fere
bori
wa
Ogun
Olorun
t'e
kori
Po
ju
awon
ota
yin
lo
E
yo!
E
yo!
Eyo
n'nu
Oluwa
e
yo!
E
yo!(Bibeli
lo
so
bee)
E
yo!
Eyo
n'nu
Oluwa
e
yo!
(T'o
ba
ri
bee)
A
f'ope
f'Olorun
L'okan
ati
ohun
wa
Eni
s'oun
'yanu
N'nu
eni
t'araye
n
yo
Gbat'a
wa
l'om'owo
On
na
l'o
ntoju
wa
O
si
f'ebun
ife
Se
'toju
wa
sibe
K'a
f'iyin
on
ope
F'Olorun
Baba,
Omo
Ati
Emi
mimo
Ti
o
ga
julo
l'orun
Olorun
kan
lailai
T'aiye
at'orun
mbo
Be
lo
wa
d'isiyi
Beni
y'o
wa
lailai(Give
Him
your
praise,
Halleluyah!)
(Oya)
Mo
m'ope
mi
wa,
f'Oba
rere
to
da
mi
si
Emi
Oluwalonibisi,
mo
wole,
juba
fun
Emi
wa
n
k'alleluya
si
Bi
gbogb'aye
dite
mo
wa
Won
gbodo
te'ri
ba
fun
Oluwa
Eyin
omo
ijo
mimo
E
dide
e
yin
Oluwa
Alleluya
ni
orin
wa
Alleluya
wa
ninu
ise
wa
Bi
aye
fe,
bi
aye
ko
Won
te'ri
ba
fun
Oluwa
Alleluya
ni
orin
wa
Alleluya
wa
ninu
ise
wa
Bi
aye
fe,
bi
aye
ko
Won
te'ri
ba
fun
Oluwa
B'oruko
Jesu
ti
dun
to
Ogo
ni
fun
oruko
Re
O
tan
'banuje
at'ogbe
Ogo
ni
fun
oruko
Re
Ogo
f'oko
Re,
ogo
f'oko
Re
Ogo
f'oruko
Oluwa
Ogo
f'ooko
Re,
Ogo
f'oko
Re
Ogo
f'oruko
Oluwa
Okan
mi
nyo
ninu
Oluwa
'Tori
O
je
iye
fun
mi
Ohun
Re
dun
pupo
lati
gbo
Adun
ni
lati
r'oju
Re
Emi
nyo
ninu
Re
(Ibanuje
o
i
mo,
ayo
l'o
ku)
Emi
nyo
ninu
Re
'Gba
gbogbo
lo
nf'ayo
kun
okan
mi
(O
f'ayo
kun
mi)
'Tori
emi
nyo
n'nu
Re
Ehehn,
oya,
bere
mo'le
k'a
jo
yin
Gbogbo
eniyan
ka'a
ma
jo
Wa
yin
Jesu
ma
ti'ju
K'a
'wo
e
s'oke
k'a
gbe
ga
Waa
ri
wonder
ninu
ope
Ibanuje
re
a
fo
lo(ah)
Ekun,
ose
a
sa
lo(ehh-eh-eh)
Oluwa
orun
on
aiye
'Wo
n'iyin
at'ope
ye
fun
Bawo
l'a
ba
ti
fe
O
to
Onibu-ore
Onibu-ore
Onibu-ore
Bawo
l'a
ba
ti
fe
O
to
Onibu-ore
Onibu-ore
Onibu-ore
Bawo
l'a
ba
ti
fe
O
to
Onibu-ore
Iwo
t'O
fe
wa
l'a
o
ma
sin
titi
Oluwa
oloore
wa
Iwo
t'O
yo
wa
ninu
'danwo
aye
o
Mimo
l'ogo
ola
Re
(Baba,
Iwo
nikan)
Baba,
Iwo
la
o
ma
sin
(Ko
s'elomiran,
Iwao
nikan
la
f'ope
fun
o)
Baba,
Iwo
la
o
ma
bo
(A
f'iyin,
f'ogo
f'oruko
yin
Sir)
Iwo
t'O
fe
wa
l'a
o
ma
sin
titi
Mimo
l'ogo
ola
Re
(Baba,
Baba
Iwo
nikan
ni)
Baba,
Iwo
la
o
ma
sin
(Ijo
e
da?
K'o
fo
s'oke,
k'o
yin
Jesu)
Baba,
Iwo
la
o
ma
bo
(Iwo,
Iwo,
Iwo,
Iwo,
Iwo)
Iwo
t'O
fe
wa
l'a
o
ma
sin
titi
Mimo
l'ogo
ola
Re
Emi
yoo
k'okiki
Re
Oluwa
Iwo
ni
o
da
mi
dide
Iwo
ni
oo
je
ki
ota
yo
mi
Ogo
ni
f'oruko
Re
Iyin,
Ọla,
Ogo
ni
fun
Ọ
Agbara
ati
ipa
jẹ
Tirẹ
Ẹgbẹrun
ahọn
ko
to
yin
Ọ
A
wolẹ,
a
juba
Rẹ
Iyin,
Ọla,
Ogo
ni
fun
Ọ
Agbara
ati
ipa
jẹ
Tirẹ
Ẹgbẹrun
ahọn
ko
to
yin
Ọ
A
wolẹ,
a
juba
Rẹ
Iba
se
pe
Oluwa
Ko
ti
wa
ni
tiwa
Lo
ye
k'awa
ma
wi
Nigbat'
esu
gbogun
dide
Ope
ni
f'Oluwa,
oba
wa
Olore
E
se
'ba
kabiyesi,
kabiyesi
le
A
f'ope
fun
Jehovah
To
gba
wa
lowo
ota
A
dupe
Oluwa
(Oya
ba
mi
f'ope
fun
o)
Ope
ni
f'Oluwa,
oba
wa
Olore
E
se
'ba
kabiyesi,
kabiyesi
le
A
f'ope
fun
Jehovah
To
gba
wa
lowo
ota
A
dupe
Oluwa
(S'e
ri)
Oluwa
wa
fun
wa,
bi
akoni
eleru
Oun
l'olori
ogun
Arogun
ma
ti
di
Arogun
ma
s'ojo
(Ah)
Gbogbo
eyin
oke,
kekere
at
nla,
eyi
to
n
gba
gudu
mo
mi
E
ma
wa
riri,
ni'waju
Oluwa
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.