King Sunny Ade - Bole Ya Koya текст песни

Текст песни Bole Ya Koya - King Sunny Ade



Ika a p′onika o
Rere a b'ẹni rere
Ika a p′onika o
Rere a b'ẹni rere
Ẹni gb'ẹkun gba l′ayé
Aya rẹ a jẹ, ọmọ rẹ a jẹ
Oun naa a wẹwẹ sẹ
Ko gbọn bi ifá mọ′ ran bi ọpẹ lẹ
(Oun naa a wẹwẹ sẹ)
(Oun naa a wẹwẹ sẹ)
Ko gbọn bi ifá mọ ran bi ọpẹ lẹ
(Oun naa a wẹwẹ sẹ)
(Oun naa a wẹwẹ sẹ)
Apa okan o ju'kan l′ayé nbi ṣẹ
Af'eyi to ba g′ori bebé o
Ko'soun t′adiyẹ t'ole f'ẹyẹ aṣa ṣe
Ko′soun t′adiyẹ
Ko'soun t′adiyẹ t'ole f′ẹyẹ aṣa ṣe
Ko'soun t′adiyẹ
Ko'soun t'adiyẹ t′ole f′ẹyẹ aṣa ṣe
Yiyọ ẹmu o
Bi t'odo kọ
Ko′soun t'adiyẹ
Ko′soun t'adiyẹ t′ole f'ẹyẹ aṣa ṣe
Ko'soun t′adiyẹ
Ko′soun t'adiyẹ t′ole f'ẹyẹ aṣa ṣe
Ko′soun t'adiyẹ
Ko′soun t'adiyẹ t'ole f′ẹyẹ aṣa ṣe
Ani yiyọ ẹmu o
Bi t′odo kọ
Ko'soun t′adiyẹ
Ko'soun t′adiyẹ t'ole f′ẹyẹ aṣa ṣe
Ko'soun t'adiyẹ
Ko′soun t′adiyẹ t'ole f′ẹyẹ aṣa ṣe
Ko ma sòún t'adiyẹ to le f′ẹyẹ aṣa ṣe o
Ko'soun t′adiyẹ
Ko'soun t'adiyẹ t′ole f′ẹyẹ aṣa ṣe
Bole ya koya ye o(Bole ya koya)
B'o ba le ya koya ṣẹ (Bole ya koya)
B′o ba le ya ko ma ya o (Bole ya koya)
Ojo p'ewe ko ku(Bole ya koya)
Ojo p′ewe ko ku(Bole ya koya)
Mo m'ẹmu m′ẹmu mo da bi ẹmu (Bole ya koya)
Mo m'ẹmu m'ẹmu mo da bi ẹmu (Bole ya koya)
Mo m′ogurọ titi mo da bi ritu (Bole ya koya)
Mo jo bẹbẹ titi ojo p′ewe ko ku (Bole ya koya)
Ojo to pa bata-koto ko pa ju ri ti (Bole ya koya)
Ojo p'ewe ko ku(Bole ya koya)
Ojo p′ewe ko ku sẹ (Bole ya koya)
Ojo p'ewe ko ku (Bole ya koya)
Mo m′ẹmu m'ẹmu mo da bi ẹmu (Bole ya koya)
Mo m′ogurọ titi mo da bi ritu (Bole ya koya)
Ojo p'ewe ko ku(Bole ya koya)
Ojo p'ewe ko ku sẹ (Bole ya koya)



Авторы: King Sunny Adé


King Sunny Ade - Classics, Vol. 2: Ekilo Fomo Ode & the Way Forward
Альбом Classics, Vol. 2: Ekilo Fomo Ode & the Way Forward
дата релиза
27-11-2001




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.