Текст песни Nitori Awa - King Sunny Ade
Wan
lọ
gb'ẹbọ
ni
oríta
mẹta
Nitori
awa
Wan
ko
jẹ
ki
babalawo
ko
simi
lalẹ
Nitori
awa
Wan
ba
kuro
ni
shọshi
wan
gba'le
ra
daun
shelọ
Nitori
awa
Eku
ina'wo
ẹran
pipa
l'ojo
jumọ
Nitori
awa
Wan
ma
gb'ẹbọ
wan
ni
ihoho
lo
gan
jọ
oru
Nitori
awa
T'aba
wi
tan
wan
ma
gbe
bíbélì
ọrọ
kiri
Nitori
awa
Kuru
kẹrẹ,
o
di
'le
alawo
Kuru
kẹrẹ
Kuru
kẹrẹ,
o
di
'le
oniṣegun
Ogun
o
ran
wa
o
Ẹ
ma
wulẹ
sáré
ka
Kuru
kẹrẹ,
o
di
'le
alawo
Kuru
kẹrẹ
Kuru
kẹrẹ,
o
di
'le
oniṣegun
Ogun
o
ran
wa
o
Ẹ
ma
wulẹ
sáré
ka
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.