Текст песни Ekilo Fomo Ode - King Sunny Ade
Awo
re
gungun
lobirin
le
ṣe
Awo
gẹlẹdẹ
lobirin
le
mọ
Bi
obinrin
fi
oju
doro,
oro
a
gbe
Ékilo
f'ọmọ
odẹ,
koma
rìnrìn
pado
Ékilo
f'ọmọ
odẹ,
koma
rìnrìn
pado
Koma
sesi
fara
ko
odidan
lojiji
Ìgbọràn
sàn
ju
ẹbọ
riru
Konko
jabẹlẹ
Kaluku
l'omi
se
ti
é
Konko
jabẹlẹ
Kaluku
l'omi
se
ti
e
Konko
jabẹlẹ
Kaluku
l'omi
se
ti
e
Konko
jabẹlẹ
Kaluku
l'omi
se
ti
e
Ki
àwon
ṣe
tiwọn
Ki
ẹyin
ṣe
t'ẹyin
Ki
àwa
ṣe
t'awa
Konko
jabẹlẹ
Kaluku
l'omi
se
ti
e
Amò
ṣá
Ékilo
f'ọmọ
odẹ,
koma
rìnrìn
pado
Ékilo
f'ọmọ
odẹ,
koma
rìnrìn
pado
Koma
sesi
fara
ko
odidan
lojiji
Ìgbọràn
sàn
ju
ẹbọ
riru

1 Ekilo Fomo Ode
2 Eni Binu Wa
3 Won Ran Mo Loja
4 Kosun Tadie
5 Bole Ya Koya
6 Esubiribiri Ebomi
7 Nitori Awa
8 Sunny Koni Ku
9 Ejire Ara Isokun
10 Rod Publicity
11 The Way Forward, Pt. 1
12 The Way Forward, Pt. 2
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.