Текст песни Yah Allah - Oriyomi Kehinde
Lawh
mahfuz
lodo
olohun,
ire
ni
moyan,
ireee
Lawh
mahfuz
lodo
olohun,
ire
ni
moyan,
ire
Kinto
sadua
emi
nkirun
Ire
ni
moyan,
ire
Mo
nyan
nafila
mose
ibaadah,
ire
ni
moyan,
ire
Wakati
marun
f'oba
olohun,
ire
ni
moyan,
ire
Robbana
Atina
Fi
duniya
Hassanatan
Wafil
akhirati,
hassanatan
Waqina
adzaba
naar
Interlude
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Allaaah!
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Allahumma
iftahliy
Abwabal
khayr
Wa
abwaba
ssalamati
Abwaba
s-sihati
Wa
abwaba
ni-imati
Wa
abwabal
barakati
Wa
abwabal
qu-wwati
Abwabal
mawadati
Abwaba
r-rahmati
Abwaba
rizqi
(Allah)
Abwabal
ilimi
(Allah)
Abwabal
magfirati
Abwabal
Jan-nnati
Yah
arhama
rohimeena
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Emi
kii
s'eru
alaimore,
oun
timofe
bamise,
maso
p'óòsé
ilahi
K'oju
mati
oruko
re
ni,
iwo
lo
fun
igbin
ni
ìkáráhún,
kito
male
da
lenu
re
Won
so
p'ógà
burewa
MashaaAllah!
Wallahi
ogun
aso,
koto
ògà
lo
lojumo
Iwo
lo
da
l'aso
aponle,
s'ore
funmi
lona
iyanu
K'enemy
ma
mo
b'ose
se,
kon
rimi
konwa
tûba
Awon
iya
toti
njewon
Ki
won
bimi
f'ona
abayo
Kinle
so
funwon
pe
iwo
lose
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Tebi
tara
nkigbe
iwo
ni,
niwon
nreti
pe
toba
de
Gbogbo
ase
toba
pa,
gbogbo
e
niwon
ma
tele
Ati
awon
tiwon
ju
e
lo,
bonse
rie
nonti
dide
Lori
chair
pe
ko
joko,
àjànàkú
o
mo
niwon
B'asemo
pe
erin
tobi
Olohun
o
wo
sisanra,
kinihun
tiò
to
won
L'allahu
se
loba,
mashaallah
Oore
olohun
ona
iyanu
Allahu
sefunmi,
kinle
so
funwon
p'ewo
lose
(Allah)
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Òshì
tin
tani
debi
arinfin,
ìshé
tinseni
debi
abuku,
ebi
tinpani
dele
ota
naa
Allaaah!
Iya
tinjeni
dele
ana,
dakun
mafi
sadanwo
Owo
topo
tio
letan
Ola
tin
weni
láwèda
Ibukun
tonle
oshi
lo
Muheeba
ton
mu
okiki
wa
Sefunmi
o
yah
robbi
Aranse
toju
àwúré
lo
Ewe
lamo
ton
sunko
Ola
olohun
làjénjétán
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Ha,
kilonfe
gan
ti
ola
olese,
ore
to
tin
lebo
tipe
Kadua
e
o
legba,
ishoro
lonba
e
finra
Qurani
ti
juwe
ashiri,
l'anabi
ba
juwe
abayo
Ji
loru
ko
joko
adura
o,
toba
d'igba
tile
ba
mo
Mu
sàrãa
ni
sise,
nigbagbo
pelu
suuru
o
Toba
dabipe
o
ma
fe
pe,
kofe
fun
e
nigbayen
ni
Tori
asiko
tiwo
fe
yen,
boya
(Allah)
o
ripe
ole
fa
akoba
Konipe
koni
jina,
yio
dae
loun
pelu
oore
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Abdul
lateef
oriyomi
Akanni
won
npe
oruko
mi
Si
t'owo
si
ipe
ola
Mo
wan
niyi
l'oko
ati
ile
Ni
gursu
pelu
ìwò
óòrùn
Ìlà
óòrùn
won
momi
naa
Moni
fans
ni
gbogbo
agbaye
Tiwon
nfemi
dokan
dokan
o
K'olohun
kemi
ke
awon
eyan
mi
Mafi
aisan
da
wa
ni
ágó
árá
Kale
gbadun
arawa
pe
Okiki
to
bunmi
allah
Ko
bamise
l'alodale
(Amin)
Yah
allah
eru
re
ni,
to
tinpe
e
fungba
tope,
mowa
gbesi
ayo
mi
ni
Oore
ni
mofe
allahu
soore,
f'eru
re
o
Allaaah
la
ilaha
illa
allahu
Lailaha
illa
allah
Allaaah
la
ilaha
illa
allaaah
Lailaha
illa
allah
Allaaaaaaa
ah,
allaaaah
Allah
la
ilaha
illa
allahu
Lailaha
illa
allah
Bi
haqqi
illa
allah,
lailaha
illa
allah
Wa
bihaqqi
arshihi,
lailaha
illa
allah
Bihaqqi
adzomatihi,
lailaha
illa
allah
Wa
bihaqqi
seyyidina,
lailaha
illa
allah
rosuli
llah,
lailaha
illa
allah
Istejibu
dua-anaa,
lailaha
illa
allah
La
tansa
murodanaa,
lailaha
illa
allah
Bihaqqi
ila
allah,
lailaha
illa
allah
Bihaqqi
ila
allah,
lailaha
illa
allah
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.