Tope Alabi - E Gbe Ga текст песни

Текст песни E Gbe Ga - Tope Alabi



E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
Oba to yi gbe aye mi pada
Eba mi gbe ga
Oun lo so ekun mi derin
Eba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
Oba to yi gbe aye mi pada
Eba mi gbe ga
Oun lo so ekun mi derin
Eba mi gbe ga oo
Bi mo ji lowuro, ma gbe ga
Owuro mi t′Oluwa ni
Olugbe ori mi soke ni
Losan ma yin Oluwa, ma gbe O ga
O fun mi lonje oojo o, ki febi pa mi
Toba dale ma yin o
Tori oun lolusoaguntan mi
Nigba kigba laye kaye
Ma gbe o ga
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
Oba to yi gbe aye mi pada
Eba mi gbe ga
Oun lo so ekun mi derin
Eba mi gbe ga oo
Mo yin Oluwa oo, mo gbe o ga
Oba to so mi deni giga
To gbekun ose lenu mi
O fibukun ore ko mi lona
O fade wura de mi lo ri
O gba mi lowo ota
Gbi gbega Olorun mi
Ore to se laye mi akaikatan, ma gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
Oba to yi gbe aye mi pada
Eba mi gbe ga
Oun lo so ekun mi derin
Eba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
Oba to yi gbe aye mi pada
Eba mi gbe ga
Oun lo so ekun mi derin
Eba mi gbe ga oo
Arabata ribiti Olódùmarè
Ọlọ́run àwọn ọlọ́run
Ma gbe ga ma gbé ga o baba o se
(Má gbé ga oo)
Ìwọ lọ lọrun ó lafiwe
rẹ, láyè lọrun
gbé ga gbé ga ó bàbà ó ṣe
(Magbe gaa ó)
Èmi ó sàì gbé ga
kuta ile, gba ṣé mi ṣé
gbé ga gbé ga ó baba ó se
(Má gbé ga ó)
Gbígbé ga o, ọba mọ yẹ irawo
gbé ga gbé ga ó bàbà ó ṣe
gbé ga o
Ọrẹ elese ayé mi pada
To sọ dẹni ọtun
gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
gbé ga o
Ìgbà mo ń bẹ láyé yín ó
Ọlọ́run ayọ' mi ò
gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
gbé ga o
yín ó títí Imi mi yóò fi pín
A lo ju bẹ lọọ
gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
gbé ga o
Ọba sọ ẹkùn mi derin
Òun kín máà yoo
gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
gbé ga o
gbé ga, Magbe ga, Magbe ga,
Ọlọ́run ayo mi oo
gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
gbé ga o
E ó, e o, ẹyin Olúwa
E ó, e o, ẹyin Olúwa
Gbógbó àgbáyé ayé, ayé
Titi ayé é, yín Olúwa
Gigiga nínú, ọlá ńlá Ọlọ′run Ọba
ayé, yín Olúwa
Titi ayé, títí ayé
Òpó lérò, ìwọ ni bàbá ṣé
Titi ayé, títí ayé
Titi ayé ẹ, yín Olúwa
Kabiyesi mo gbósu ba
Ose ó bàbà
Oba titi aye oo, ose o
Ọlọ'run pípé ni o
A lai labawon
Oba titi aye oo, ose o
Kari aye kari ola
Ọba ń bẹ nibi gbogbo
Oba titi aye oo, ose o
A ro àlá, àdììtú Olódùmarè
Oba titi aye oo, ose o
Alágbára ńlá ń
Omi ń mi le aye
Oba titi aye oo, ose o
A báni já, je
A ń pe nibi, ọrọ ó ń su wọn
Oba titi aye oo, ose o
Àìkú, aisa, aidibaje, Ọlọ́run ti ṣe ènìyàn
Oba titi aye oo, ose o
Oyigiyigi ọba sún, Kìí de rún gbe
Oba titi aye oo, ose o
Òkúta ìdí gbó lu ni o, Ilé ìṣo agbára mi
Oba titi aye oo, ose o
Chineke idinma Imela oo
Oba titi aye oo, ose o
Abasi so so o, Abasi amanamo
Momiri maku abo o, wame e
Oba titi aye oo, ose o
Almasiu séríkí ngigi, nagode yesu
Oba titi aye oo, ose o
Asa agbara kiki da agbara
Owo nla arogun ti di ooo
Oba ńláńlá ńlá
To lo kanrin kese to lo kan rinnnnn
Keeeeeese



Авторы: Tope Alabi


Tope Alabi - Angeli Mi
Альбом Angeli Mi
дата релиза
12-04-2007




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.