Текст песни Odara Ni Ife - Tope Alabi
E
fi'ba
fun
Un,
e
yin
I
o
Awon
angeli,
won
n
yi
ite
Re
ka
Gbogbo
eda
eniyan,
e
yin
I
bo
ti
ye
E
fi'ba
fun
Un,
e
yin
I
o
Awon
angeli,
won
n
yi
ite
Re
ka
Gbogbo
eda
eniyan,
e
yin
I
bo
ti
ye
K'orin
tuntun
s'Oluwa
iwo
okan
mi
E
ma
yo
n'nu
Oluwa
eyin
olododo
Nitori
iyin
ye
fun
Oluwa
E
fi
duru
yin
Oluwa
t'ohun
t'eelo
orin
K'orin
naa
s'oke
kikan
k'aye
ko
gbo
o
Nitori
ile
aye
kun
f'aanu
Re
E
fi'ba
fun
Un,
e
yin
I
o
Awon
angeli,
won
n
yi
ite
Re
ka
Gbogbo
eda
eniyan,
e
yin
I
bo
ti
ye
Emi
t'a
dalarr
ti
a
dariji
Emi
t'Oluwa
gba
la,
t'O
se'gun
fun
Okan
mi
k'orin
yin
Oga
ogo
Awon
angeli
juba
Re
lojoojo
Agbaagba
lorun
f'iba
yi
ite
Re
ka
Pipe
lo
je
ogo,
lailakawe
E
fi'ba
fun
Un,
e
yin
I
o
Awon
angeli,
won
n
yi
ite
Re
ka
Gbogbo
eda
eniyan,
e
yin
I
bo
ti
ye
Mo
f'eru
gbe
E
ga,
mo
yin
Oga
ogo
O
so
ibu
omi
po,
O
gba
okun
jo
O
s'oro,
o
si
ti
se
mo
yin
O,
Oluwa
E
fi'ba
fun
Un,
e
yin
I
o
Awon
angeli,
won
n
yi
ite
Re
ka
Gbogbo
eda
eniyan,
e
yin
I
bo
ti
ye
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
Ninu
opo
ife
lo
ragabo
mi
Oore
ofe
Re
ni
mo
n
je
Ibukun
Re
to
po,
lo
je
k'emi
po
Ninu
ogo
Re
lokan
mi
n
yo
Ohun
gbogbo
lO
fi
se
'ke
mi
Oba
Onike,
didara
ni
O
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
O
gba
mi
lowo
ogun
idile
Mariwo
mi
yo
laarin
igbago
Ogun
ibi
a
ti
bi
d'atemole
Bi
t'ota
se
po
to
won
dake
jeje
Apenimadani,
didara
ni
O
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
Alainironu
o
ni
le
dupe
Mi
o
ni
ya
'baramooreje
Olori
ogun
to
f'ife
ja
'ja
ikoro
lori
aye
mi
mo
dupe
Ope
mi
ka
sai
gun
lailopin
titi
laye
Aabo
Re
ti
o
ka
lori
ebi
mi,
komboki
oore
Olorun
to
dara
ni'ke,
ige,
Iwo
ni
maa
sin
o
Onife
alailodiwon,
Oloore
mi
O
se
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
Igba
ti
ogun
dide
ija
oloro
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
ti
eni
a
ro
bi
ore
d'ota
gbangba
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
eti
ore
gbo
ogun,
to
f'ese
fe
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
t'afeniferere
o
le
rerin
mo
o
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
t'ebi
wa
ninu
ipaya
ogun
oro
o
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
T'abanijiroro
o
le
beere
eni
mo,
o
ma
se
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Olufe
owon,
Iwo
nikan
n
mo
ri
o
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
ti
ile
kan
roro,
ti
ito
enu
gbe
lau
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
t'adura
at'aawe
di
sisa,
aisoje
rara
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Igba
yi
mo
wa
r'arisa
eniyan
bi
won
ti
n
jehun
eni
t'on
pani
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
As'ologo
asun
mala
lakun
nirin
ajo
aye
yi
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Iwo
to
m'ooto
oro,
to
mo
'bere
to
mo
'bi
ti
o
pin
si
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Arinurode
Olumoran
okan
lo
yo
mi
o
Ose
(Iwo,
Iwo,
Iwo
nikan
lo
n
gbe
mi
ro)
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
Didara
ni
ike,
didara
laabo
Didara
ni
ife,
didara
laabo
O
po
loore,
O
po
ni'bukun
o
Mo
wa
f'iba
fun
O,
Oba
t'o
n
s'ohun
gbogbo
ninu
ohun
gbogbo
1 Oba Aseda
2 Odara Ni Ife
3 Oruko Oluwa
4 Oruko Tuntun
5 Mo Mope Mi Wa
6 Ikoko Oga Ogo
7 Aye Yii
8 Oro Kan Soso
9 Tipa Tikuuku
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.