Текст песни Oro Kan Soso - Tope Alabi
Oro
kan
soso
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Beeni
mo
wi
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Oro
laseda
fi
d'aye
at'orun
Ohun
gbogbo
to
wa
ninu
e,
oro
lo
fi
da
B'aye
at'orun
ba
yi
pada,
oro
l'Olorun
yio
wa
titi
lai
Tori
oro
ledidi
ohun
gbogbo
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Oro
lagbara
e
wa
wo'di
oro
aye
Ohun
t'aye
n
pe
loro
ni
gbolohun
Ninu
oro
aye
ni
won
n
so
ofo
Ninu
oro
won
ni,
ase
Ohun
oro
aye
n
se
fun
aye
'Jamba
lo
po
ninu
won
Oruko
t'aye
ba
p'oro
ni
yio
je
Ibi
ni
won
fi
n
se
fun
'ra
won
Eda
gbogbo
ti
n
gb'aye
e
ma
ba
mi
bo
o
Ibudoko
ero
to
n
lo
si
irin
ajo
Laperosoko
ti
n
p'ariwo
E
wole,
hundred
naira
lowo
ori
enikan
Onikaluku
wole
soko
Loko
ba
kun
ni
won
ba
si
Won
m'ori
le
irin
ajo
won
Igba
t'an
mi
a
gb'owo
oko
tan
pata
Baba
kan
lo
ko
to
lohun
o
ni
san'wo
pe
O
san
hundred
naira,
o
fe
gba
forty
naira
pada
Gbogbo
ero
to
mbe
ninu
oko,
won
ko
ha!
wipe
baba
se
bee
ti
gbo
tele
Conductor
lohun
o
ni
gba
laabo,
baba
lohun
o
ni
won
kun
Enikan
ninu
oko
lohun
a
fi
kun
Baba
ba
ni
ko
ni
dara
f'eni
ba
fi
kun
Gbogbo
ero
to
mbe
ninu
oko
ba
gb'enu
won
dake
Igba
baba
de
'bi
to
n
lo
Lo
ba
wo
conductor
sokale
loko,
lo
ba
ni
o
gbe
Ka
to
wi,
ka
to
fo,
ero
ti
pe
le
won
lori
Ijamba
laye
ma
fi
n
wa
(beeni)
B'agbara
aye
ba
ti
n
gun
won
(e
o
ni
se
won)
B'ika
ba
n
gun
eniyan
ibi,
won
a
maa
to'ja
tase
kiri
beeni
Oro
ni
won
fi
n
ja,
e
wa
wo'di
oro
t'aye
n
pon
le
Lo
ba
p'ase
lati
'nu
oro,
t'a
wa
ninu
Olorun
ti
a
ko
ri
Ko
to
wi
tan,
conductor
ti
bo'so
sonu
Lo
ba
mo'ri
le
'gbo
S'e
ti
r'aye
oro
agbara
aye,
opelope
arakunrin
kan
T'o
m
be
ninu
oko
to
j'omo
Olorun,
to
m'oro
iseda
To
da
aye,
to
d'ohun
gbogbo
Oro
Olorun
to
nipa
oro
eyi
ti
a
ti
ko
wipe,
ko
s'ohun
ija
kan
ti
a
se
si
o
ti
yio
pa
o
lara
Ati
pe
t'aa
leni
naa,
ti
n
wi,
to
si
n
se,
nigba
ti
Oluwa
ko
p'ase
re
o
Nitorina,
ni
oruko
Jesu
Olugbala,
conductor
pada
wa
'bi,
wo'so
k'ori
e
si
pe
Lara
ba
ro
baba
oloro
aye,
a
b'e
o
r'oro
to
n
gb'oro
mi
Bi
ko
ba
se
ti
Jesu,
opo
eda
lo
ti
d'eja
ko
s'awon
won
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
kan
soso,
o
le
tun
se,
oro
kan
soso
Eniyan
inu
aye,
e
je
k'a
fura
o
Satani
n
s'oro
bi
agbon
Elomiran
ki
a
to
bi
won
o,
lowo
awon
ota
ti
te
won
Elomiran
nigba
t'a
bi
won
tan,
laarin
egbe,
nibi
ise,
owo
ika
t'a
gbe
leni
lori
ta
o
mo,
lorisirisi
ijamba
ti
n
se
ni
E
je
ka
gb'adura
eniyan
o
K'aye
ma
f'oro
won
tun
ni
da
Mo
f'owo
d'eleda
mi
mu
K'ori
mi
ma
gba
'bode
oro
o
Oro
kan
soso
to
s'eda
aye
e,
oro
kan
ni
Oro
kan
soso
to
n
gbe
oro
mi,
oro
kan
soso
Gbogbo
ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
iseda,
o
so
won
di're
pada,
oro
o
Oro
kan
soso
to
s'eda
aye
e,
oro
kan
ni
Oro
kan
soso
to
n
gbe
oro
mi,
oro
kan
soso
Gbogbo
ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
iseda,
o
so
won
di're
pada,
oro
o
Oro
kan
soso
to
s'eda
aye
e,
oro
kan
ni
Oro
kan
soso
to
n
gbe
oro
mi,
oro
kan
soso
Gbogbo
ohun
ti
a
ti
f'oro
baje
ninu
aye
mi
o
Oro
iseda,
o
so
won
di're
pada,
oro
o
1 Oba Aseda
2 Odara Ni Ife
3 Oruko Oluwa
4 Oruko Tuntun
5 Mo Mope Mi Wa
6 Ikoko Oga Ogo
7 Aye Yii
8 Oro Kan Soso
9 Tipa Tikuuku
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.