Текст песни Oruko Oluwa - Tope Alabi
Maa
yin
O,
Olorun
t'O
dara,
t'O
n
s'ohun
gbogbo
fun
mi
o
Emi
o
yin
O,
imole
to
n
f'ona
han
mi
oo
e
Ore
Re
koja
siso,
o
kamomo
eee
Ona
Re
ma
pe
mi
o,
arinye
ni
o
Eeee
(titobi
Oga
nla)
Alade
Ogo,
iba
Re
o
Olorun
to
dara,
iwa
Re
wu
mi
o
e
Mo
wa,
mi
o
ri
oba
to
dabi
Re
ninu
gbogbo
oba
Alade
Ogo,
iba
Re
o
Olorun
to
dara,
iwa
Re
wu
mi
o
e
Mo
wa,
mi
o
ri
oba
to
dabi
Re
ninu
gbogbo
oba
Awon
t'orun
n
f'ogo
fun
Un,
Elemi
eda
O
na'wo
Re
lat'orun
ja
aye
o
O
n
rin
lori
igbi
okun
Oruko
Re
nikan
lo
ko
aje
ya
Agbara
Re
nikan
ni
ko
le
pin
Ko
s'eni
to
le
gb'ogo
Re
pin
lailai
Alade
Ogo,
iba
Re
o
Olorun
to
dara,
iwa
Re
wu
mi
o
e
Mo
wa,
mi
o
ri
oba
to
dabi
Re
ninu
gbogbo
oba
Alade
Ogo,
iba
Re
o
Olorun
to
dara,
iwa
Re
wu
mi
o
e
Mo
wa,
mi
o
ri
oba
to
dabi
Re
ninu
gbogbo
oba
Gbogbo
aye
n
wariri
labe
Re
Eda
gbogbo
o
lo
gba
O
loga
Ohun
gbogbo
to
da
lorun
at'aye
Ko
le
ri'di
agbara
Re
o
ee
Won
o
le
ri'di
agbara
Re
o,
Aseda
mi
Alade
Ogo,
iba
Re
o
Olorun
to
dara,
iwa
Re
wu
mi
o
e
Mo
wa,
mi
o
ri
oba
to
dabi
Re
ninu
gbogbo
oba
Alade
Ogo,
iba
Re
o
Olorun
to
dara,
iwa
Re
wu
mi
o
e
Mo
wa,
mi
o
ri
oba
to
dabi
Re
ninu
gbogbo
oba
Oluwa
Oluwa,
oruko
Re
niyi
Ni
gbogbo
aye
o,
oruko
Re
niyi
Ninu
awon
orun
o,
oruko
Re
niyi
Apeepetan,
Oloruko
pupo
Titi
lailai,
oruko
Re
ko
le
pin
Titi
aye,
oruko
Re
ko
le
pin
Oluwa
Oluwa,
oruko
Re
niyi
Ni
gbogbo
aye
o,
oruko
Re
niyi
Ninu
awon
orun
o,
oruko
Re
niyi
Apeepetan,
Oloruko
pupo
Titi
lailai,
oruko
Re
ko
le
pin
Titi
aye,
oruko
Re
ko
le
pin
Alagbara,
Olododo,
Atobiju
lOluwa
Alaanu
o
lOluwa,
oruko
Re
n
gba
ni
la
Oruko
Re
n
gbe
ni
ro,
oruko
Re
n
so
ni
d'oloro
Oloruko
aperire
(aperire
apedahun
loruko
Jesu)
Oluwa
Oluwa,
oruko
Re
niyi
Ni
gbogbo
aye
o,
oruko
Re
niyi
Ninu
awon
orun
o,
oruko
Re
niyi
Apeepetan,
Oloruko
pupo
Titi
lailai,
oruko
Re
ko
le
pin
Titi
aye,
oruko
Re
ko
le
pin
Oruko
Re
n
ja
fun
ni
Oruko
Re
n
gbe
iku
mi
Oruko
Re
n
f'ona
han
ni
Oruko
Re
n
t'aye
se
Ibi
gbo'ruko
Re,
o
pare
Okunkun
gbo
o
wole
lo
Oluwa
Oluwa,
oruko
Re
niyi
Ni
gbogbo
aye
o,
oruko
Re
niyi
Ninu
awon
orun
o,
oruko
Re
niyi
Apeepetan,
Oloruko
pupo
Titi
lailai,
oruko
Re
ko
le
pin
Titi
aye,
oruko
Re
ko
le
pin
Oruko
ti
ko
le
baje,
ni
mo
be'ri
fun
Oruko
ti
o
le
pin,
tion
sir!
Oruko
Oluwa
o,
ile
iso
Oruko
Oluwa
ni
ipa,
agbara
ni
Oruko,
oruko,
oruko,
oruko,
oruko
nlanla
Emi
ni,
Ona
Otito,
Iye
Ilekun,
Kokoro
Imole,
Ododo
Jesu
Kristi,
Messiah
Okuta
aidigbolu,
Odo
aguntan
rere
Apata
ayeraye
e
1 Oba Aseda
2 Odara Ni Ife
3 Oruko Oluwa
4 Oruko Tuntun
5 Mo Mope Mi Wa
6 Ikoko Oga Ogo
7 Aye Yii
8 Oro Kan Soso
9 Tipa Tikuuku
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.