9ice - Pete-pete Lyrics

Lyrics Pete-pete - 9ice



Uuuhh, sebe le ma sun?
(Sebe le ma-?)
Ojo re bi ana ta gbominira, 1960
Nigba yen, things easy
Gege bo se wi
Ta rugbo, tomidan
L'o n dunu, pa tin gbominira
Omi inira, indeed abi ewo naira wa
Ilu polukulumushu
Tewe, tagba lon jeyan won nisu
Abe ori? Ewe eri, sugbo e ofewi
Abe ori? Agba eri, atenuje lofe pa yin
Pete-pete tana ni popa
Eni bataba kolo mofe ni
Sebe lema sun?
Teba sope omo nkan-kan
Eyin aro lema waa (sebe la maa)
Mewa nsele o
Sebe lema sun? (Sebe lema sun un?)
Eni woseju akan o
Eyin aro lema waa
Mewa nsele o
Kini suuru tio lere?
Kini ise, ti ko sere?
Won sa leyan tio loruko
Okuku sise oden rere e
Aah, ede sope a siwa l'omode
Nkan sa l'eiye nje kagbado tode
9ice, oro gidi loso
Oro to o nilari loso
Anlati fi laka yesi
Kasoro sibi torowa
Sebe le masun oo? (Sebe le masun un?)
Eyin aro lema wa a (sebe lema sun un?)
Mewa nsele o
Sebe lema sun un?
Teba ro seju akan
Eyin aro lema wa o
Mewa nsele o
Odi asiko ibo yen
Won wa s'adugbo
Won asomo je-je
Eje kan wole tan
Gbogbo eje tan je (kai!), la wo kese
Toba tun se were la siko ibo
Won ani kodo tolo bere
Won a senu mere
Kalo-kalo gbe nkan mi senu uye (kalo-kalo senu uye)
Afira aditu ti iwole
Talo dibo fun un?
Pasan ta fi na yale
Onbe lori aja fun un un
Odo elo tunramu
Ema jo anpagbon ni funfun
Fun yin
Mowi temi ii—
Asegbe kan kosi oo
Asepamo lowa (beni, beni, beni, beni—)
Ase sile labo waba
Emi oti iku, mo sile sise
Mo sile fowo wewo
Mo sile tule mise iiiii
Sebe lema sun un?
Teba sope omo nkankan
Eyin aro lema wa a
Mewa nsele o
Sebe le ma sun un?
Eni woseju akan o
Eyin aro lema waa
Sebe le maa? (Mewa nsele o)
Lema sun un
Asa o se, omo nla
Lema sun un
Lema sun un
Lema sun un
Sun un



Writer(s): Lara George


9ice - Tradition
Album Tradition
date of release
05-12-2009




Attention! Feel free to leave feedback.