Brymo - Fura Sára Lyrics

Lyrics Fura Sára - Brymo



O pami l'ekun
O wa a funmi l'akara je
Mo sunkun mo gbon'ju
Oni nsare lo'soja
Bowunmi nbu'gi je
Aaha aaah aaaaha aaaha aaaaha aahaa aaha
Oloomi dakun jowo o, dakun jowo o
Ye'gbo t'elegan
Ye'gbo t'elegan
Ye'gbo t'elegan
Fura siwon
Ogba'ja on'ija ja
O'nja fun'araata
Toba ya wa lanu gbaga
Wa l'emi mo se'aida
Aaha aaah aaaaha aaaha aaaaha aahaa aaha
Obinrin yi dakun jowo o, dakun jowo o
Ye'gbo t'elegan
Ye'gbo t'elegan
Ye'gbo t'elegan
Fura s'ara



Writer(s): Olawale Olofo'ro


Brymo - 9: Èsan
Album 9: Èsan
date of release
08-09-2021




Attention! Feel free to leave feedback.