Lyrics Ààrẹ - Brymo
Ere
okuta
ati
gilasi
Bo
ṣana
si,
o
ma
ta
papa
Ọlọpa
wa
o,
o
ma
da
rin
wa
Oreke
lẹwa
jẹ'a
ṣere
Ere
okuta
ati
gilasi
Bo
ṣana
si,
o
ma
ta
papa
Ọlọpa
wa
o,
o
ma
da
rin
wa
Oreke
lẹwa
jẹ'a
ṣere
Ere
okuta
ati
gilasi
Bo
ṣana
si,
o
ma
ta
papa
Ọlọpa
wa
o,
o
ma
da
rin
wa
Ẹku
owurọ
Iroyin
lati
igboro
la
mu
wa
kan
yin
leti
Wọn
ni
ni
owurọ
yii,
awọn
ọmọ
èés!
Wọn
ti
ja
wọ'gboro
Wọn
dẹ
ti
n
dana
sun'le
Wọn
ti
n
dana
s'oko
At'ọkọ
ayọkẹlẹ
ati
i'ti
o
yọkẹlẹ
Gbogbo
ẹ
lọ
dana
sun
Ẹ
gbe'le
yin
o
Ẹ
ṣọra
yin
o
Ẹ
pe
awọn
ọmọ
yin
s'ọdọ
Iyi
ti
o
ba
lọ
s'ile
iwe,
k'o
joko
Ki
olọọrun
ki
o
ma
ṣọ
gbogbo
wa
o
Layọ
ẹ
ṣe
Aàrẹ
n
bọ
l'ajo
Awọn
ọmọwe
taku
s'ọrun
l'aafin
Awọn
ọjẹlu
duro
ṣigidi
ọkọ
ofurufu
Emi
baba
ọba,
mo
duro
ṣigidi
Ori
mi
lo
gbe
mi
k'ore
Aàrẹ
n
bọ
l'ajo
Awọn
ọmọwe
taku
s'ọrun
l'aafin
Awọn
ọjẹlu
duro
ṣigidi
ọkọ
ofurufu
Emi
baba
ọba,
mo
duro
ṣigidi
Ori
mi
lo
gbe
mi
k'ore
Attention! Feel free to leave feedback.