Brymo - Òkùnkùn Lyrics

Lyrics Òkùnkùn - Brymo



N ò fara pamọ′ fún òló mi
Èé ṣe t'ọ′rọ' rẹ ń fún mi
N ò ṣ'olùgbàlà
Òótọ′ dùn mo wárí o
Káwọn ọ′rẹ' mi mi yọ lódodo
Ìfẹ′ nìkan fún mi
s'ẹnìkan mi yọ
Àjò layé
N ò mọ mo ṣe o
Mo fura ibẹ′ ni ń lọ
Òkùnkùn lati
Òkùnkùn ń lọ



Writer(s): Olawale Olofo'ro



Attention! Feel free to leave feedback.