Brymo - Méjì Méjì Lyrics

Lyrics Méjì Méjì - Brymo



iyẹ′ mi fo
ri'rè
waju, w′oké
Ìrè
ìjò mọlẹ, mo tún takasúfè
O dún mọ' òó
O dún mọ' òó
O dún mọ′ òó òó
O dún mọ′ òó
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Méjì méjì làá d′àiyé ò
Ìfẹ rẹ mí, o jìn gángan
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Méjì méjì làá d′àiyé ò
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Ìfẹ rẹ mí, ò jìn gángan
Méjì méjì làá d′àiyé ò
Ọrẹ, dákun lọ
tàràkà, mo ṣubu
Kín kọ òun món sọ
Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì
Ẹsìn o gbani
Ìwà o lani
Òún wùn 'nì nwa
Ọrẹ, dákun lọ
Mo tàràkà, mo ṣubu
Kín kọ òun món sọ
Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì
Ẹsìn o gbani
Ìwà o lani
Òún wùn'nì nwa ni
fi iyẹ fo
Mo rí′rè
′wájú mo w'òkè
Ìrè
ijó mọlẹ, mo tún takasúfè
O dùn mọ óò
O dùn mọ óò
O dùn mọ óò
O dùn mọ óò
Méjì méjì làá d′àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Ìfẹ rẹ mí, o jin gángan
Méjì méjì làá d′àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d′àiyé óò
Ìfẹ rẹ mí, o jin gángan
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d′àiyé óò
Ìfẹ rẹ o jin gángan
Méjì méjì làá d′àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d′àiyé óò
Ìfẹ rẹ o jin gángan
Méjì méjì làá d'àiyé óọ′



Writer(s): Olawale Olofo'ro


Brymo - 9: Èsan
Album 9: Èsan
date of release
08-09-2021




Attention! Feel free to leave feedback.