King Sunny Ade feat. The Golden Mecury of Africa - Ona Mi La Lyrics

Lyrics Ona Mi La - King Sunny Ade




Ọnà mi la (Ọna mi la)
Ọnà mi la (Ọna mi la)
Kosi ibi to dàbí ọna olùgbàlà
To fún níyè
To sọ mi d′aṣẹgun
Wahala, ìbànújẹ lọnà mi o
Ọnà mi la peregede
Ọnà mi la o
Ọnà mi (Ọnà mi la)
Ọnà mi la (Ọna mi la)
Kosi ibi to dàbí ọna olùgbàlà
To fún níyè
To sọ mi d'aṣẹgun
Wahala, ìbànújẹ lọnà mi o
Ọnà mi la peregede
Ọnà mi la o
Mo l′oluwa
Gbogbo òkè ìṣòro mi adi ipẹtẹlẹ
Mo ma ti l'oluwa
Gbogbo òkè ìṣòro mi adi ipẹtẹlẹ
A dara funmi
Igba ayé mi a dara l'oju ọta mi
A dara funmi
Igba ayé mi a dara l′oju ọta mi
A tumi lara
Gbẹgẹ niran koko lara wa o
Mo ma ti l′oluwa
Gbogbo òkè ìṣòro mi adi ipẹtẹlẹ
Mo ti l'oluwa ọba
Gbogbo òkè ìṣòro mi adi ipẹtẹlẹ
A dara funmi
Igba ayé mi a dara l′oju ọta mi
A dara funmi o
Igba ayé mi a dara l'oju ọta mi
A tumi lara o
Gbẹgẹ niran koko lara wa o
Mo ma ti l′oluwa
Gbogbo òkè ìṣòro mi adi ipẹtẹlẹ
Ani mo ti l'oluwa
Gbogbo òkè ìṣòro mi adi ipẹtẹlẹ
A dara funmi laye
Igba ayé mi a dara l′oju ọta mi
A dara funmi tọmọ tọmọ
Igba ayé mi a dara l'oju ọta mi
A tun wa tumi lara
Gbẹgẹ niran koko lara wa o
A tumi lara
Gbẹgẹ niran koko lara wa o



Writer(s): King Sunny Ade


Attention! Feel free to leave feedback.