Lyrics Gaga 'yoru-Bar Cypher' - Averse , Sola Shittu , Lc Beatz
Ahhh
(Hook)
God
And
God
Alone
lo
n
je
ti
GAGA
O
mu
mi
jade
kuro
ni
para
Ko
ma
se
lo
miran
mo
to
dara
Lo
je
kin
ma
pariwo,
say
me
I'm
going
GAGA(gagaga)
Me
I'm
going
GAGA(gagagagagaga)
Me
I'm
going,
me
I'm
going
GAGA(gagagagaga)
Ni
bo
ni
motife
Bere
si
ni
ṣàlàyé,
farabale
ko
tẹ
ti
gbọ
mi
alaye
eleyi
gidi
gan
Mi
o
wa
be
like
e
ṣeré
at
all
o
I'm
talking
my
father,
yeah
Wọ
ni
kilode
to
ṣé
ma
n
ka
mi
lara
to
ba
ti
d
ọ'rọ'
Jésù
gan
Mo
ma
n
sọ
fun
wọn,
òun
lo
renew
mi,
mi
o
sọ'rọ'
starch
kan
kan
Ama
kip
blowing
the
horn
O
gbudọ
yé
wọn
ni,
bi
ti
tadiyẹ
Mo
de
ti
sọ
wípé,
mi
o
ni
gbenu
dake
till
every
of
my
padi
hears
So
I
gat
to
press
on
even
ti
n
ba
rina
lo
iron,
My
God
is
able,
lo
save
me
from
the
den
lọ'jọ'
kini
àná
Devil
no
fit
direct
me
Ko
ki
n
ṣé
Tunde
Kelani
The
dude
is
under
my
feet,
a
fi
bii
ti
shoe
filami
Ọlọhun,
o
ti
gbé
mi
lékè,
mo
fo
lókè
like
I
am
le'kele'ke,
lọ
bi
Leke
Òun
ni
GAGA,
Òun
ni
first
and
the
last
Ama
tell
everywhere,
moo
ni
ṣéẹ'kẹ'
(HOOK)
Emi
mimọ
la
wa
mọ,
omo
a
o
fẹ
mo
yan
But
I'll
hold
it
down
for
my
street,
mo
ṣi
leniyan
Wo
lọ
n
binu
for
their
kinape,
wọ
n
faraki
Jésù
mi
lo
ran
mi
wa
Àwọn
ni
mo
ba
wa
bi
Lege
o
Dotun
lege
o
Lori
mic
yi,
I'm
a
heavy
weight
Jegede
o
Wọn
o
lé
gbé
mi
o
Ee
ri
ran
wo
le
ni
o
Moral
presence
la
wa
n
gbé
kiri,
a
tun
gbé
wọlé
o
Justice
for
the
beatz
Oba
Reegy
ma
na
Barrister
Egbon
MC,
oni
la
ti
sọ'rọ',
mo
ma
ba
wi
Sir
GAGA
ni
mo
gbé
so
ri
Mii
gbejo,
orí
medusa
But
we
travel
on
the
snakes
kọja
lo
ri
medusa
(Gagagagagagagaga)
gbaso
ké
Me
I'm
going
(Gagagagagagaga)
Awa
lo
mo
F-A-D-A(fada)
Oti
gbé
wa
sókè
L-A-D-A(lada)
Therefore,
awa
ko
le
P-A-D-A(pada)
Ìgbàgbọ'
mi
duro
lori
G-A(ga)
Mo
ti
gbekelele
G-A(ga)
Oya
fada
lada
pada
gaga
Sharp
as
alapata
dagger
Jah
Jehovah
Rapha
El
Elyon
El
Shaddai
El
Akrrmm
Mo
ka
n
lẹ,
mée
ko
bàtà
Pako
ẹ'mí,
ko
saye
butter
Mo
fọlọhun
belohun,
maa
je
normal,
That's
my
prayer,
simply
because
Mi
o
ki
n
ṣé
bastard
I
no
be
BAAAASTARD
My
papa
na
thunder
Papa
na
fire
So
ti
mi
o
ba
lé
ṣé
signs
and
wonders
Fédéfọ'
without
rehearsal
Ṣé
lo
yẹ
kẹ
wa
mi
wale,
tu
mi
láṣọ,
ti
mi
si
ta,
fọ
mi
létí
(GA...
you
think
I'm
joking
uhn...
GA)
(Me
I'm
going,
me
I'm
going
GAGA)
(Me
I'm
going
GAGA)
To
ba
ti
gbọ
GAGA,
ko
dee
n
ṣé
bii
ti
white
lady
yen
Think
about
my
father
ti
won
o
lé
ba,
ti
o
de
ré
bikan
E
àwọn
kan
wa
fẹ
ma
diṣi
father
mi
But
anyway,
mo
gbé
sori
bi
eni
ti
o
ye
lawa
ni
Àwọn
kan
ni
kolewerk,
ẹ
sọ
fun
wọn
kan
dá
padà
Tori
GAGA
gan
ni
movement
and
the
mode
is
on
okada
Ìtùmò
ẹ
ni
pé,
a
o
ma
lé
pada
seyin
If
u
hatin
on
us,
Oyo
lo
wa
bi
e
ni
n
gbé
ni
Iseyin,
you
know
I
know
say
u
bean
cake
bi
eni
n
tákárà
Ogbeni,
ti
o
ba
ni
Jésù,
ṣé
lo
taraka
Keep
it
logged,
bi
iru
Jamo
to
kọ
raga
Ogbeni
ko
ni
túmọ',
to
ba
ti
lè
sé
fun
GAGA
woos
(HOOK)
Ọlọ́run
ni
kan
ni
kan
ṣoṣo
Ẹ'jẹ'
ọ'dọ'
àgùntàn,
my
logo
Iresi
mi
o
dawa,
na
the
word
be
my
dodo
Sùúrù
mi
ti
lérè
Ọlọ́run
ti
ṣògo
E
ma
bi
mi
lérè
bi
oro
yen
ṣé
ma
n
dogo(dogo)
Yaro
yaro,
ibanuje
paro
E
ni
to
ba
fẹ'ràn
Jésù,
oya
jẹ
a
kolabo
E
mi
ti
kọ
Jé
lori
key
C
Lojojumo
ni
mo
n
fi
se
nu
gan
ni
bibi
Mo
ti
n
di
blessing,
mo
ti
n
di
blessing
Gba
bẹ
yẹn,
no
more
relenting
No
more
relenting,
gba
bẹ
yen
Mi
o
ni
sun
seyin,
mi
o
ni
sun
seyin
Gba
bẹ
yen
Mo
ti
n
gba
mi
layé,
ni
mo
n
lu
titititi
kẹti
GAGA!!
GA
GA
GA
1 Paiwo
2 Dide
3 Rereni
4 Gaga 'yoru-Bar Cypher'
5 Pewon
6 Adua
7 All I Need
8 Felele
9 Do Dat
10 Rintintin
11 Hallele
12 Waboshewa (Bonus Track)
Attention! Feel free to leave feedback.