Lyrics Afoju - Tope Alabi
To
ba
n
rin
l'okunkun
Ko
le
mo,
afoju
ni
To
ba
n
jeun
eleera
Ko
le
mo,
afoju
ni
To
ba
r'omoge
to
rewa
eeeh
Ko
le
mo
rara
Okunkun
o
da
ma
so
mi
s'okun
osan
Eledua
To
ba
n
rin
l'okunkun
To
ba
n
rin
l'okunkun
ko
le
mo
rara
Ko
le
mo,
afoju
ni
afoju
ni
To
ba
n
jeun
eleera
eh
Ko
le
mo,
afoju
ni
afoju
ni
bawo
lo
se
fe
mo
To
ba
r'omoge
to
rewa
eh
ah
Ko
le
mo
rara
agaga
eeh
Okunkun
o
da
ma
so
mi
s'okun
osan
Eledua
Oju
L'obara
o,
okunkun
o
da
Eda
mi
gbo
Etewo
adura
araye,
ka
ma
f'opa
rin
Amin
o
Eniyan
buru
ninu
aye
won
le
pokun
meko
fun
ni
beeni
aye
buru
Aye
mi
d'owo
re,
ba
mi
so,
mo
mi
n
bebe
o
aye
mi
d'owo
re
o
To
ba
n
rin
l'okunkun
ma
je
k'omo
araye
so
mi
Ko
le
mo,
afoju
ni
s'okunkun
e
To
ba
n
jeun
eleera
Ko
le
mo,
afoju
ni
To
ba
r'omoge
to
rewaa
eeeh
Ko
le
mo
rara
ko
le
mo
rara
Okunkun
o
da
ma
so
mi
s'okun
osan
Eledua
ma
so
mi
s'okunkun
osan
o
Gbogbo
abarapa,
e
ranti
abirun
e
ma
ranti
won
E
ma
se'ranlowo,
ema
di
kun
won
l'eru
rara
Ti
won
to
won
gbe,
oro
aye
kanpa
o
Ara
aye
e
buru
To
ba
fe
ni
loju,
won
a
tun
f'ata
s'enu
Aye
To
ba
n
rin
l'okunkun
Ko
le
mo,
afoju
ni
Bawo
lo
se
femo
To
ba
n
jeun
eleera
Ko
le
mo,
afoju
ni
At'owuro,
at'osan,
at'ale
To
ba
r'omoge
to
rewa
eh
lo
dudu
l'oju
afoju
Ko
le
mo
rara
ko
le
mo
o
Okunkun
o
da
ma
so
mi
s'okun
osan
Eledua
Ma
so
mi
s'okun
ooh
Oju
L'obara
o,
okunkun
o
da
Eda
mi
gbo
eda
mi
gbo
Etewo
adura
araye,
ka
ma
f'opa
rin
unh
unh
Eniyan
buru
ninu
aye
won
le
pokun
meko
fun
ni
eh
Aye
mi
d'owo
re,
ba
mi
so,
mo
mi
n
bebe
o
ba
mi
so
o
Baba
To
ba
n
rin
l'okunkun
To
ba
rin
l'okunkun
Ko
le
mo,
afoju
ni
Bawo
lo
se
femo
To
ba
n
jeun
eleera
To
ba
n
jeun
Ko
le
mo,
afoju
ni
To
ba
n
jeun
alayan
To
ba
r'omoge
to
rewa
eh
eeeh
Ko
le
mo
rara
ko
le
mo
rara
Okunkun
o
da
ma
so
mi
s'okun
osan
Eledua
Ma
so
wa
s'okun
ooh
To
ba
n
rin
l'okunkun
ah
ah
ah
ah
Ko
le
mo,
afoju
ni
Gbogbo
abarapa
To
ba
n
jeun
eleera
Ko
le
mo,
afoju
ni
E
toju
afoju
yin
To
ba
r'omoge
to
rewa
eh
Mo
nigbagbo
pe
Ko
le
mo
rara
lojo
ojo
kan
Okunkun
o
da
ma
so
mi
s'okun
osan
Eledua
won
a
l'aju
bi
ti...
Album
From the Archive of Tope Alabi - Sound Track Compilation (Version 1)
date of release
10-07-2015
1 Ayemi Ayemi
2 So Irin Mi
3 Elenini Amutorunwa
4 Afoju
5 Mowowa Aye
6 Asiri Bibo
7 Omo Laso
8 Eyin Okunrin
9 Eso Lore Iwa
10 Mase Mase
11 Mumi Debe
12 Taba Nso
13 Ebiire Ko
Attention! Feel free to leave feedback.