Tope Alabi - Elenini Amutorunwa Lyrics

Lyrics Elenini Amutorunwa - Tope Alabi



Aditu loro yi o eh
Ole o, ole koko
Kori ko gbani o lo'wo won
Elenini amutorun wa
(Aditu loro yi o}
Aditu loro yi o eh (ole koko)
Ole o, ole koko (ahh)
K'ori ko gbani o lo'wo won (k'ori ko gbani o lo'wo won)
Elenini amutorun wa
Eyin waye se rere, e mura ogun
Awotele yin adura o, tori ko se duro wo
Elenini n bani bo laye
Tibi tire n la dale aye (awon kan ibi)
Aditu loro yi o e (be la won kon ise ire)
Ole o, ole koko (kori man je ba won sa'gbako)
K'ori ko gbani o lo'wo won (ah ah ah)
Elenini amutorun wa
Ton ba se l'adura, ko s'amin o
T'on ba se l'epe, ko ko o
Eye f'owo yepere mu aye o
E sora tori aye le koko (eh eh)
Aditu loro yi o e (k'elenini ko ma bere o hun ti mi o ni)
Ole o, ole koko (eleda gbami o)
K'ori ko gbani o lo'wo won (ah)
Elenini amutorun wa (bami re won so nu)
Eyin waye se rere, emura ogun
Awotele e yin adura o
Tori ko se duro wo
Elenini n bani bo laye
Tibi tire n l'adele aye (ah ah)
Aditu loro yi o e (aditu)
Ole o, ole koko (ole eh eh)
K'ori ko gbani lo wo won (ah)
Elenini amutorun wa (elenini amutorun wa)
Aditu loro yi o e (oh oh)
Ole o, ole koko (o ma le)
K'ori ko gbani o lo'wo won (k'ori ko gbani o)
Elenini amutorun wa



Writer(s): Patricia Temitope Alabi


Tope Alabi - From the Archive of Tope Alabi - Sound Track Compilation (Version 1)




Attention! Feel free to leave feedback.