Lyrics Aye Yii - Tope Alabi
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
(This
world,
aye
t'a
wa
yi
o)
Nitori
aye
- eda
gbagbe
Olorun
Nitori
aye
- eeyan
gbagbe
iku
o
Aye
yi,
aye
eh
- aye
eh
eh
ah
ah
ah
aye
yi
Eniyan
fe
aye,
aye
o
feran
won
Won
ni
aye
n
d'ogbo,
aye
o
kuro,
eniyan
lo
tun
s'aye
di
tuntun
Aye
ja
gba
lowo
eeyan
o
fi
tun
'ra
e
se,
eda
o
mo
ja
gba
lowo
aye
k'on
fi
t'orun
won
se
Eda
gbagbe
oh
eh,
eniyan
gbagbe
o
P'aye
yii
kii
se
t'eniyan
Eda
wa
na'ja
laye
ni
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
Ara
ki
lo
n
wa,
t'o
n
wa
to
bee
t'o
n
sa
kijo
kijo
Ore
ki
lohun
to
mu
wa,
t'o
fe
di
pada
lo,
tell
me
I
want
to
know
Aye
n
w'owo,
tori
e
pa'ra
won
lekun,
ah
o
se
Tori
ile,
tori
aso,
alumoni
oro
repete,
eniyan
tori
agbara
di
kiniun,
ikoko
ajorijapa
Won
a
ma
bu
ramuramu,
a
di
iduro
o
si,
ibere
o
si
o,
bi
eni
to
gb'odo
mi
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
Eniyan
lo
n
p'aye,
aye
o
p'eeyan
Eda
n
fe'fun
p'aye,
aye
o
se
kirakita
Aye
o
se
wahala
(En)
Eniyan
lo
n
wo
laasigbo
(Oin)
S'enu
jeje
mu'ti
laye
(En)
Aye
o
lese,
aye
mirin
(Oin)
Eniyan
n
ro
lese
tori
aye
(En)
Aye
o
loju,
aye
n
riran
(Oin)
Oju
eda
n
wa'mi
tori
aye
(En)
Aye
logba
eniyan
lo
n
ro'ko
e
(Oin)
Aye
o
loyun,
aye
n
bimo
(En)
Omo
t'eniyan
n
bi,
aye
tun
n
ni
won
(Oin)
Eniyan
o
gbon
mo
pa'ye
n
pamo
o
ki
iku
to
de
La
i
lojo
lori
eniyan
n
gbo
Aye
f'arungbo
ojo
ori
eeyan,
eda
lo
n
sise
oro
f'aye,
t'aye
fi
n
tuntun
si
lojoojo
Aye
d'oloro,
eniyan
n
ku
'ku
otosi
Aye
de
gbon
'gbon
akuusin
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
Eniyan
ronu
o,
k'aye
to
je
o
mo
orun
re
Omo
to
so
'le
nu,
n
lo
so
apo
iya
ko
Olugbala
ke
tantan
o,
omo
maa
bo
Oga
ogo
feran
re
o,
omo
yara
wa
Ara
ma
ko
'fe
Jesu
yi
o,
wa
gba
'rapada
to
f'eje
se
This
is
practical
love
that
I've
ever
seen
in
display
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
Ife
amutorunwa,
igbala
yi
On
lo
le
se
Ona
isinmi
miran
ko
si,
afi
ninu
ife
Oluwa
Ko
s'eni
to
le
fe
o
to
Jesu
Ultimate
price
He
has
paid
Pansaga,
agbere
wa,
ole,
ika,
e
yara
wa
Apanilekun
e
sare
ma
bo
Iborisa
at'akogun
ja
'lu
Eyin
akogun
ja
orile
ede
E
gb'ohun
Eleda
yin,
t'On
f'ife
pe
yin
o
Ore
ma
d'aniyan
si,
ko
ma
so
p'oo
gbo
O
n
pe
o,
omo
wa
gba
'gbala
S'e
ti
r'alaso
to
ku
ti
won
d'aso
e
mo
(E
je
n
gbo)
S'e
ti
r'eleran
to
ku
ti
won
di
maalu
mo
(Aye
e
gbo)
Onipetesi
wo
lo
ku,
ti
won
di'le
e
mo
(K'e
je
a
gbo)
Aye
agbara
n
f'alagbara
sile,
ogun
a
di
t'awon
to
le
jagun
Oro
a
di
t'awon
ti
o
mo'di
oro,
ma
fi
'gbala
re
sofo
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
Aye
aye
(Aye
e
e
o
o
o
o)
This
world
eeh
(hmn
hmn
hmn
hmn
oh
this
world,
aye
yi)
1 Oba Aseda
2 Odara Ni Ife
3 Oruko Oluwa
4 Oruko Tuntun
5 Mo Mope Mi Wa
6 Ikoko Oga Ogo
7 Aye Yii
8 Oro Kan Soso
9 Tipa Tikuuku
Attention! Feel free to leave feedback.