Tope Alabi - Oruko Oluwa Lyrics

Lyrics Oruko Oluwa - Tope Alabi



Maa yin O, Olorun t'O dara, t'O n s'ohun gbogbo fun mi o
Emi o yin O, imole to n f'ona han mi oo e
Ore Re koja siso, o kamomo eee
Ona Re ma pe mi o, arinye ni o
Eeee (titobi Oga nla)
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Awon t'orun n f'ogo fun Un, Elemi eda
O na'wo Re lat'orun ja aye o
O n rin lori igbi okun
Oruko Re nikan lo ko aje ya
Agbara Re nikan ni ko le pin
Ko s'eni to le gb'ogo Re pin lailai
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Gbogbo aye n wariri labe Re
Eda gbogbo o lo gba O loga
Ohun gbogbo to da lorun at'aye
Ko le ri'di agbara Re o ee
Won o le ri'di agbara Re o, Aseda mi
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Alagbara, Olododo, Atobiju lOluwa
Alaanu o lOluwa, oruko Re n gba ni la
Oruko Re n gbe ni ro, oruko Re n so ni d'oloro
Oloruko aperire (aperire apedahun loruko Jesu)
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Oruko Re n ja fun ni
Oruko Re n gbe iku mi
Oruko Re n f'ona han ni
Oruko Re n t'aye se
Ibi gbo'ruko Re, o pare
Okunkun gbo o wole lo
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Oruko ti ko le baje, ni mo be'ri fun
Oruko ti o le pin, tion sir!
Oruko Oluwa o, ile iso
Oruko Oluwa ni ipa, agbara ni
Oruko, oruko, oruko, oruko, oruko nlanla
Emi ni, Ona
Otito, Iye
Ilekun, Kokoro
Imole, Ododo
Jesu Kristi, Messiah
Okuta aidigbolu, Odo aguntan rere
Apata ayeraye e



Writer(s): Patricia Temitope Alabi


Tope Alabi - Oruko Tuntun
Album Oruko Tuntun
date of release
12-12-2014




Attention! Feel free to leave feedback.