Lyrics Oruko Tuntun - Tope Alabi
Olorun
to
da
mi
w'aye
o,
lo
ni
oruko
mi
amutorunwa
Eleda
to
da
mi
leniyan
lo
so
mi
loruko
akoko
Emi
lologo
alayanmo
ire,
mo
w'aye
wa
f'ogo
Olorun
han
Aisiki
ire,
sabaabi
idunnu
lemi
eniyan
Olorun
to
da
mi
w'aye
o,
lo
ni
oruko
mi
amutorunwa
Eleda
to
da
mi
leniyan
lo
so
mi
loruko
akoko
Emi
lologo
alayanmo
ire,
mo
w'aye
wa
f'ogo
Olorun
han
Aisiki
ire,
sabaabi
idunnu
lemi
eniyan
Eto
Olorun
ni
emi
je
Aseda
f'inu
f'edo
f'ife
da
mi
O
mo
mi
ni
iri
Ohun
gangan
Mi
o
ku
si'bi
kan,
O
da
mi
daradara
Emi
lamo
t'owo
Adaniwaye
mo
Eemi
Aseda
ni
iwalaaye
mi
Oju
ogo
Re
ni
iriiran
mi
akoko
Ipa
lo
fi
se
mi
s'inu
iya
mi
Ara
nla
owo
Oga
ogo
ni
mi
Emi
leniyan
Olorun
to
da
mi
w'aye
o,
lo
ni
oruko
mi
amutorunwa
Eleda
to
da
mi
leniyan
lo
so
mi
loruko
akoko
Emi
lologo
alayanmo
ire,
mo
w'aye
wa
f'ogo
Olorun
han
Aisiki
ire,
sabaabi
idunnu
lemi
eniyan
Irin
ajo
eda
wa
s'aye,
esu,
ota,
elenini
eniyan
n
duro
Ami
ibi
to
tele
eda
bo
ni
satani
t'a
le
sokale
lat'orun
O
n
bu
ramuramu,
o
n
kanra,
lo
fi
n
fi'bi
han
eda
leemo
Eni
ba
w'aye
(w'aye)
Eeyan
to
n
gb'aye
(gb'aye)
E
ma
sai
bikita
p'aye
kun
fun
ibi
Olorun
to
da
wa,
ko
da
wa
tori
ibi
Olorun
to
da
mi
w'aye
o,
lo
ni
oruko
mi
amutorunwa
Eleda
to
da
mi
leniyan
lo
so
mi
loruko
akoko
Emi
lologo
alayanmo
ire,
mo
w'aye
wa
f'ogo
Olorun
han
Aisiki
ire,
sabaabi
idunnu
lemi
eniyan
Ti
Oluwa
ni
ile,
ati
ekun
re
Ohun
gbogbo
to
da
s'oke
eepe
lo
dara
Satani
lo
so
won
d'ibi
Eniyan
e
ma
se
ran
lowo
Ma
je
k'an
f'ibi
so
e
loruko,
ire
ni'wo
je
o
ma
gbagbe
Oruko
a
maa
ro
ni
Jowo
ma
se
bi
alaigbon
Ohun
t'aa
ba
n
je
la
o
da
Ara
e
gb'oruko
t'awon
eeyan
n
pe
'ra
won
(oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
E
gb'oruko
t'eniyan
n
pe
'ra
re
(e
gb'oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
Oloriburuku,
talaka
n'on
n
pe
'ra
won
(oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
Agan,
were,
alaarun
ni
won
n
pe
'ra
won
(e
gb'oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
Omugo,
didinrin
ni
won
n
pe
'ra
won
(oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
Alayebaje,
atoole
n'on
n
pe
'ra
won
(e
gb'oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
Aletilapa
ni
won
n
p'omo
won
(oruko
t'on
n
pe
'ra
won)
Ah
e
o
mo
p'ohun
t'a
ba
pe
loruko
o
lagbara
lori
eda
Ohun
ti
o
n
la
koja
ooo,
jowo
ma
fi
pe
'ra
e
mo
Enikeni
to
ni
'dojuko
isese
kan,
e
ma
fi
pe
loruko
Ma
f'epe
san
epe,
maa
ko
oruko
buburu,
satani
lo
n
je
baun
A
ti
d'ele
aye
na,
dandan
ni
k'a
laagun
k'a
to
yo,
sise
pelu
ero
ire,
wa
a
yo
Awon
elomiran
a
ni
nile
awon
bi
won
o
logun
odun
ni'gbeyawo
won
o
ni
le
bimo
Won
a
ni
nile
won
(won
kii
le
ko'le)
Won
a
ni
nile
awon
(won
kii
gbo
k'on
to
ku)
Idojuko
won
(n'on
fi
n
pe
'ra
won)
A
ni
aisan
to
n
se
ohun
(n
lo
pa
'ya
ohun)
Won
a
tun
fun
loruko
(alaarun
idile)
Won
a
lohun
gangan
(logun
ebi
won)
Eda
n
f'oruko
isoro
(p'oriki
ara
re)
Won
a
ni
b'o
ti
n
se
won
(n'ile
awon
niyen)
Eda
e
so'ro
to
dara
jade,
ero
alaafia
lOlorun
ni
si
wa
Ma
f'ogun
enu
se
'ra
e
pa
Pe
'ra
e
ni
hun
to
fe
je
Oruko
to
dara
lOlorun
so
mi
Oruko
to
logo
o
lEleda
n
pe
mi
Oruko
to
dara
ni
emi
n
je
Aseda
mo
mi
ire
Emi
ako'rewaye
Emi
agb'ayesayo
Mi
o
ya'gan
lona
kankan
Aisiki
ola,
wura
oro,
ara
owo
Aseda,
lemi
eniyan
Igbagbo
n
se
pupo
loro
eda
(alaisan
ti
o
ni
'gbagbo
ko
le
gba
'wosan)
Ireti
logun
f'oruko
tuntun
(alainireti
ko
le
kuro
loju
kan)
Eda
segun
nipa
oro
enu
re
(iku
ati
iye
wa
lori
ahon)
Ma
s'ahon
d'ida
fi
sa
ara
e
si
wewe
(wa
a
jere
ohun
to
ba
f'enu
so)
Eni
to
da'na
s'aaro
ti
o
gbe
'hun
le'na
(o
daju
ko
ni
'hun
se)
O
kan
fe
ya'na
lasan
ni,
igbagbo
ni
yo
ba
ero
e
sise
Ja
ijangbara
fun
oruko
rere,
oruko
lo
n
ro
ni
Oruko
to
dara
l'Olorun
so
mi
Oruko
to
logo
o
l'Eleda
n
pe
mi
Oruko
to
dara
ni
emi
n
je
Aseda
mo
mi
ire
Emi
ako'rewaye
Emi
agb'ayesayo
Mi
o
ya'gan
lona
kankan
Aisiki
ola,
wura
oro,
ara
owo
Aseda,
lemi
eniyan
Eda
to
n
gbe
'nu
aye,
yara
pada
s'odo
Aseda
On
lo
mo'di
oro,
On
lo
le
yanju
e
F'Adaniwaye
se
edidi
aye
re,
mura
lati
s'atunse
gbogbo
Ko
lati
je
oruko
t'aye
n
so
ni,
to
n
ba
ayanmo
wo
'jakadi
Ore
b'Olorun
d'owo
po
o,
k'aye
e
ko
le
toro
Ore
b'Olorun
laja,
ko
le
j'oruko
tuntun
Oruko
to
dara
lOlorun
so
mi
Oruko
to
logo
o
lEleda
n
pe
mi
Oruko
to
dara
ni
emi
n
je
Aseda
mo
mi
ire
Emi
ako'rewaye
Emi
agb'ayesayo
Mi
o
ya'gan
lona
kankan
Aisiki
ola,
wura
oro,
ara
owo
Aseda,
lemi
eniyan
Obedi-Edomu
j'oruko
tuntun
(o
j'oruko
tuntun)
Bartholomew
j'oruko
tuntun
(o
je
oruko
tuntun)
Jakobu
j'oruko
tuntun
(o
j'oruko
tuntun)
Dafidi
j'oruko
tuntun
(o
je
oruko
tuntun)
Maria
Magdaleni
j'oruko
tuntun
(o
j'oruko
tuntun)
Soolu
j'oruko
tuntun
(o
je
oruko
tuntun)
Peteru
apeja
j'oruko
tuntun
ooo
(o
j'oruko
tuntun)
At'emi
nipa
eje
odo
aguntan,
mo
gba
ire,
to
je
ini
mi
pada
Olorun
to
da
mi
w'aye
o,
lo
ni
oruko
mi
amutorunwa
Eleda
to
da
mi
leniyan
lo
so
mi
loruko
akoko
Emi
lologo
alayanmo
ire,
mo
w'aye
wa
f'ogo
Olorun
han
Aisiki
ire,
sabaabi
idunnu
lemi
eniyan
Emi
t'a
da
(Emi
t'a
da)
Laworan
Olorun
(Olorun)
Emi
eda
(Emi
eda)
Mo
ri
ojurere
(Ojurere)
Mo
loore
ofe
to
ga
julo
Emi
lori
(Emi
lori)
Mi
kii
se
iru
o
(Lailai)
Emi
t'a
da
(Emi
t'a
da)
T'ewa
t'ogo
Olorun
(Olorun)
Lat'odo
Aseda
o,
ola
mi
o
lakawe
A
ti
fi
oruko
tuntun
pe
mi,
emi
A
ti
fi
oruko
tuntun
pe
mi,
Amin
A
ti
fi
oruko
tuntun
pe
mi,
emi
A
ti
fi
oruko
tuntun
pe
mi,
Amin
A
ti
fi
oruko
tuntun
pe
mi,
emi
A
ti
fi
oruko
tuntun
pe
mi,
Amin
...
1 Oba Aseda
2 Odara Ni Ife
3 Oruko Oluwa
4 Oruko Tuntun
5 Mo Mope Mi Wa
6 Ikoko Oga Ogo
7 Aye Yii
8 Oro Kan Soso
9 Tipa Tikuuku
Attention! Feel free to leave feedback.