Lyrics Mimo L'Oluwa (Medley) - Tope Alabi
Mimo
l′Oluwa
o
(mimo)
Angeli
nwo
mike
o
(mimo)
Awon
orun
nwo
mike
(mimo)
Egbagbeje
irawo
o
(mimo)
Mimo
l'Oluwa
(mimo)
Angeli
nwo
mike
o
(mimo)
Awon
orun
nwo
mike
(mimo)
Egbagbeje
irawo
o
(mimo)
Agbagba
merinlelogun
(mimo)
N′origun
merin
aye
o
(mimo)
Ati
oke,
ati
ile
(mimo)
Seri
nwo
ke
o
(mimo)
Tani
yo
gori
oke
Oluwa
(mimo)
Tabi
tani
yo
duro
ni'be
o
(mimo)
Eni
ti
o
ni
owo
mimo
(mimo)
Ati
aya
funfun
(mimo)
Mimo
l'Oluwa
(mimo)
Mimo
o
mimo
(mimo)
Mimo
o
mimo
o
mimo
(mimo)
Mimo
o
funfun
nene
ni
(mimo)
Kabiyesi
Eledumare
Oba
mimo
(mimo)
Oba
la
gbogbo
aye
ete
riba
fun
oba
ti
oda
gbogbo
adarihunhun
Oba
ti
oni
emi
inu
eniyan
pata
Oni
kokoro
aye
l′
lowo
Adagodo
emi
gbogbo
eniyan
Olu
kogan
orun
ajosi
edumare
Ibinigbi
awuwo
bi
atele
Opa
tiri
kole
o
ko
orun
Minimi
ojo
ti
jeki
ara
odehin
Orun
wawa
ti
o
pada
bo
si
po
Olorun
ti
o
′so
osupa
di
ale
ti
oun
t'
oru
Oba
ti
ose
ohun
gbogbo
ni
asiko
ni
asiko
Oba
ti
ole
fi
eni
′yi
ti,
ti
a
ole
fi
eyi
re
ti
laila
Are
la
Oba
ti
eni
kan
obi,
ti
obi
omo
kari
gbogbo
aye
koropodo
Olowo
ori
gbogbo
aye
pata
pata
ni
Oniwa
funfun
Oba
dake
se
un
ti
enikan
ole
se
un
si
Inu
ogo
gangan
ni
oti
fo
owu
Ol'
ogo
ti
oju
ogo
lo
ni
Ki
abi
o
ko
si
Emi
o
je
fi
o
sere
Afi
eni
ti
o
ba
fe
gba
query
l′odore
Mi
oje
fi
oju
di
o
Oba
ti
ose
wo
lo
ju
wo
Oti
e
leti
Aledibaje
ni
o
Baba
la
kun
Baba
mi
Ole
gbi
yeke
Gbogbo
eni
ti
oba
mo
riri
Oluwa
Ete
riba
ewa
riri
fun
Oba
nki
shi
Ibere
ati
opin
Olorun
ajanakun
ti
mi
igbo
kiji
kiji
kiji
Ti
abubu
ti
a
le
buto
to
posi
ni
gbogbo
ojo
Eje
ka
sapa
fun
Oba
rere
ti
aba
mo
riri
Emi
inu
awon
woli
mimo
A
tobi
tan
alainiye
ko
koja
kika
Terere
ko
ja
riri
to
Gigun
l'
alopi
Ailetunwo,
adawunro,
adawunso,
adawunse
Olulu
awon
orun,
oke
la
ari
owu
masiti
Attention! Feel free to leave feedback.