Lyrics Nigbati Mo Ro O - Tope Alabi
Lati
inu
oyun
Titi
di
omo
owo
o
Igba
mo
wa
lomo
owo
Awon
ota
gba
wipe
iku
o
pa
mi
Mo
ra
ko
ro
de
ile
olodia
awon
ti
o
fe
n
waye
rara
Baba
o
sho
mi,
ore
re
yi
o
lakawe
Lati
irakoro
titi
di
omo
irinse
o
sho
mi
Titi
mo
fi
wa
di
agbalagba
o
Igba
ti
mo
ro,
Ise
Iyanu
re
laye
mi
Mo
wa
ri
pe
o
oga
o
pupo
Igba
ti
mi
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
mo
ri
pe
o
ga
Mo
ri
pe
o
ga
Baba.
Igba
ti
mo
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
mori
pe
oga,
mori
pe
oga
pupo.
Igba
ti
mi
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
more
ri
pe
o
ga
Mo
ri
pe
o
ga
Baba.
Igba
ti
mo
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
mori
pe
oga,
mori
pe
oga
pupo.
Ogun
ti
eniyan
ja
n′agba,
o
poju
Ogun
ewe
lo
Tori
eni
aye
ba
le,
ti
aye
o
ri
mu
ni
ogun
to
sanra
doju
ko
Idi
ti
aye
fin
le
ni,
Oye
aye,
Olorun
mi
mo
ooo
Oju
ogun
laye
je
feni
to
waye
o
wa
se
rere
Mo
wa
ronu
jinle
Aanu
re
lori
aye
mi
Emi
ri
pe
o
ga
o,
pupo
Igba
ti
mi
ro
anu
re
lo
ri
mi
Mori
pe
oga,
mo
ri
pe
o
ga
Mo
ri
pe
o
ga
Baba.
Igba
ti
mo
ro
anu
re
lo
ri
mi
Mori
pe
oga,
mori
pe
oga,
mori
pe
oga
pupo.
Igba
ti
mi
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
mo
ri
pe
o
ga
Mo
ri
pe
o
ga
Baba.
Igba
ti
mo
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
mori
pe
oga,
mori
pe
oga
pupo.
Ose
Olorun,
Iwo
lo
je
ki
ewu
aye
fo
mi
da
Iya
to
je
mi,
o
je
ko
je
mi
gbe
o,
baba
o
seun.
A
pe
omo
lowo
eyin
Oluso
agun
fun
mi
Olorun
iwo
ni
Iwo
lo
gbe
mi
ro,
eniyan
o
le
seyi
o
afi
iwo
O
gbe
mi
so
ke
gogoro,
Osuba
re
o
baba
Eyi
ni
mo
se
isiro
fun
titi,
ogbon
ori
mi
ko
gbe
Igba
ti
mi
ro
ife
nla
re
Lori
mi
Mori
pe
oga,
more
ri
pe
o
ga
Mo
ri
pe
o
ga
Baba.
Igba
ti
mo
ro
ife
nla
re
lori
mi
Mori
pe
oga,
mori
pe
oga,
mori
pe
oga
pupo.
Igba
ti
mi
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
more
ri
pe
o
ga
Baba.
Igba
ti
mo
ro
ise
iyanu
re
laye
mi,
Mori
pe
oga,
mori
pe
oga,
mori
pe
oga
pupo.
Olorun
to
ga
owa
loke
Olorun
to
be
ninu
aye
Okere
titi,
ogba
mimo
eniyan
Owa
lotun
wa,
owa
lo
si
wa
Ayika
wa
gbogbo,
owa
ni
be
Ohun
ni
olorun,
afeti
lu
Kara
Larin
alawo
dudu
o
n
sise
e
lo
Eyin
re
eniyan,
mo
rin
ise
re
Alawo
funfun
won
teriba
fun
Alayi
mo
n
kon,
won
beere
wipe
Tani
olorun,
ta
lolorun
Ayanfe
ema
da
won
lo
wun
pe
Ibi
gbogbo
lo
wa
eh
Olorun
agbaye
Ibi
gbogbo
lo
wa
eh
Ani
ko
si
ibiti
oju
olorun
ko
to
Ibi
gbogbo
lo
wa
Olorun
nla
apejuba,
arayerorun
Ibi
gbogbo
lo
wa
Ibi
gbogbo
lolorun
gbe
Ibi
gbogbo
lo
wa
O
nbe
laye,
emi
awon
woli
to
to
Ibi
gbogbo
lo
wa
Oro
gbe
inu
omo
eniyan
fo
mu
Ibi
gbogbo
lo
wa
Oti
saju
aye
de,
omo
inu
aye
ati
eyin
aye
Ibi
gbogbo
lo
wa
Ibi
gbogbo
lo
wa
olodumare
Ibi
gbogbo
lo
wa
O
nbe
larin
awon
angeli
mimo
Ibi
gbogbo
lo
wa
Ko
si
ibiti
e
pe
olorun
si
ti
o
wa
oh
Ibi
gbogbo
lo
wa
Ibi
gbogbo
lo
wa
baba
oh
Ibi
gbogbo
lo
wa
Olorun
ajanaku,
ibi
gbogbo
lo
wa
baba
Ibi
gbogbo
lo
wa
O
nbe
lokan
re
ti
o
ba
gba
laye
Ibi
gbogbo
lo
wa
Ibi
gbogbo,
ibi
gbogbo
lo
wa
Ibi
gbogbo
lo
wa
Attention! Feel free to leave feedback.