Tope Alabi - Angeli Mi Lyrics

Lyrics Angeli Mi - Tope Alabi



Áńgẹ′lì mi ò, Áńgẹ́lì mi Oku ìṣe mi ṣe padà lẹ'yìn mi Atọ′ọ'nà mi
gbogbo ọ̀nà l'ańgẹ′lì mi Olóore mi Ẹni ta yàn fún mi Olùtọ́jú mi,
ṣe aláàbò mi lọ Atánràn mi ni gbogbo ona l′ańgẹ'lì mi Ẹlẹ′dàá yan
áńgẹ́lì tìnìyàn Látọmọwọ' l′ańgẹ'lì ti bẹ′rẹ' ìṣe A fúnni nígbà
O mọ'ràn táadá Òun lóle sàkàwé ẹni nígbà tọ′ọ′rọ' bárújú Olóore mi
Ẹni ta yàn fún mi Olùtọ́jú mi,
ṣe aláàbò mi lọ Atánràn mi ni gbogbo ona l′ańgẹ'lì mi Lóòótọ′
Sẹ'ni le r′ohunkóhun gbà fi fun látọ'run Ọ'run láti yànpín
Ohun dáyé o Ṣùgbọ́n áńgẹ́lì ẹnikọ′ọ′kan lóhún sa labojuto wọn
Ìṣe takuntakun táńgẹ'lì ńṣe jẹ′ ka dàbí ẹni mọ'ọ′se Bíbélì
Sọ nínú ayé a ó ìpọ́njú Ṣùgbọ́n tújúká Olúwa ṣẹ'gun aye
O ṣalábàápàdé ẹni ìpọ́njú le gbilẹ′ láyé wa Àjálù lorisirisi
Torí èṣù ò fẹ' ka gbádùn ayé àjùmọ'bí ó kan tàánú ó ẹni Ọlọ′run rán
Síni ńṣe ni loore Áńgẹ́lì fi ra ẹ′ ṣènìyàn fa ni lọ'wọ′ sókè re
Ibi giga Ẹni kòkó rẹ' dẹ′ ayé a lóhùn lo mo
Lọ Agbẹjọ'rò ò kùnà l′ańgẹ'lì ẹni jẹ' o Ẹni t′
Ọlọ′run rán mi, ó yàtò ṣẹ'ni to rán ò To ti áńgẹ́lì rẹ,
ma ṣojú méjì díẹ′ káàtò,
lerò p'ańgẹ′lì rẹ káwó gbera torí èyí bẹ kiri,
Ohun gbogbo nígbà àti àkókò fún Tani áńgẹ́lì rẹ, Ṣe wòlíì rẹ ni,
àbí olùṣọ'àgùntàn Ọ′rẹ', Bàbá,
Màmá Torí ẹnikẹ́ni lọ jẹ' tóò ti mọ′ wọn O lọ sìwà wọn,
ó fún wọn o O jìnnà re rẹ,
Ko lọ kẹ′yìn wọn Àdúrà olódodo ó ń ṣíṣe agbára Ọlọ́run kìí se
Onídán O gbàdúrà késì tètè de Ọ'tọ tún kogun ó ṣẹ o ka mọ
Bi ti ṣẹ′ Ibi tógun ẹlòmíràn ṣẹ' alelúyà gbàgbé ẹ′sín
rántí ọ' jẹun sẹ′yìn abọ',
èèrà ò rin bi a ti jẹun ṣe ṣì gbọ' rárá
Olúwa lo mọ ohun gbogbo to se À mọ ó ti lẹ′nìkan t′
Ọlọ'run gbé ètò ayé wa lọ′wọ'.
Arákùnrin yẹ inú rẹ wò, obìnrin yẹ yín wo Olóore mi,
K′ańgẹ'lì fi sílẹ′ Áńgẹ́lì Atonàn mi,
Jọ'wọ' gbé mi síbi ayọ′ mi ṣẹ Áńgẹ́lì yàn fún jọ′wọ' gbé mi
síbi ayò mi o Ibi lọ mi ó lọ Jọ′wọ' mi sónà mi máse lo
Ire gbogbo ko mi a jẹ tèmi,
àmín Olóore mi Ẹni ta yàn fún mi Olùtọ́jú mi,
ṣe aláàbò mi lọ Atánràn mi ni gbogbo ona l′ańgẹ'lì mi




Tope Alabi - Angeli Mi
Album Angeli Mi
date of release
12-04-2007




Attention! Feel free to leave feedback.