Lyrics Opin Irin Ajo (Remix) - Tope Alabi
Bi
e
ba
n
gbo
t′omode
n
ge
'gi
ni
′gbo
Agba
lo
le
mo
'bi
to
mi
a
wo
si
B'omode
ba
rin
irin
ajo
loju
agba
O
le
ma
ba
agba
mo
ni′le
to
ba
de
o
Irin
ajo
eda
laye,
Olorun
lo
mo
Opin
irin
ajo
k′a
fi
s'adura
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o
k′a
jagunmolu
Bi
e
ba
n
gbo
t'omode
n
ge
′gi
ni
'gbo
Agba
lo
le
mo
′bi
to
mi
a
wo
si
B'omode
ba
rin
irin
ajo
loju
agba
O
le
ma
ba
agba
mo
ni'le
to
ba
de
o
Irin
ajo
eda
laye,
Olorun
lo
mo
Opin
irin
ajo
k′a
fi
s′adura
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o
k'a
jagunmolu
Opin
irin
ajo
o
o
laye
Abalo
ababo
wa
ninu
aye
Laisi
laala
ko
ma
si
isinmi
Eni
to
maa
yege
o,
a
rin
un
wi
O
fe
lowo,
o
fe
ko′le
o
ninu
aye
Laisi
'ranwo
Olorun
ofo
lo
ma
ja
si
Eni
fe
se
rere
o,
dandan
a
w′oju
Olorun
Esu
o
ni
fun
o
lookan,
ko
ma
fi
gb'eedegbaa
Ona
eburu
lonitohun
yen
a
fi
parun
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o,
ka
jagunmolu
Laala
ninu
aye,
irin
ajo
aye
Ogun
to
n
ja,
t′Olorun
nse
won
a
re
koja
lo
Opin
irin
ajo
ni'ku,
a
gbe
ni
ju
langba
si
koto
Eni
ti
ku
ni'sinmi,
iyen
p′orisirisi
Ibi
ta
o
re,
b′a
d'orun
lo
ja
ju
o
Ibo
lodo
temi
tire,
ore
je
ka
roo
Oba
je
ko
san
wa
o,
ka
b′Olorun
nile
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o,
ka
jagunmolu
Jesu
ti
wa
s'aye
lati
ku
fun
emi
ati
iwo,
ore
ma
se
ko
ife
Jesu
yi
o
Nitori
o
san
fun
eniyan
lati
ma
wa′ye
rara,
ju
pe
k'o
pada
s′orun
apaadi
lo
Ore
mi
mo
n
be
o,
iku
Jesu
Kristi,
mase
je
ko
ja
s'asan
Oniwakuwa
ronu
k'o
lo
ja′wo
Alagbere,
oniwokuwo
k′e
ya
so
se
Ole,
janduku,
e
ku
ireti
ojo
idajo
K'aborisa
ko
pa
un
ti
o
soro
ti
k′o
sin
lOhun
E
ye
bo
satani
lowo
k'e
tun
f′enu
ko
Jesu
S'eke
s′ajo
ko
s'eni
t'o
gb′alubosa
e
gbo,
to
maa
fi
ka
′la
o,
iyen
d'eewo
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o,
ka
jagunmolu
Aye
o
ni
′boji,
orun
ni
'boji
aye
Eni
da
′mi
siwaju
lo
n
te
'le
tutu
Eni
lo
s′ajo
to
mi
a
de
ti
o
ti
ferese
Iyen
gbe
'se
ile
re
f'onisona
ko
w′eyin
wo
rara
K′o
to
dele,
iji
ka'ja,
ojo
wole
p′eru
Iboji
a
da
ninu
ile
to
ti
d'aatan
Eni
ye
ko
wole
mu′mi
sinmi
a
tun
ko
sise
Opin
irin
ajo,
isinmi
lo
ye
k'o
je
Bi
e
ba
n
gbo
t′omode
n
ge
'gi
ni
'gbo
Agba
lo
le
mo
′bi
to
mi
a
wo
si
B′omode
ba
rin
irin
ajo
loju
agba
O
le
ma
ba
agba
mo
ni'le
to
ba
de
o
Irin
ajo
eda
laye,
Olorun
lo
mo
Opin
irin
ajo
k′a
fi
s'adura
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o
k′a
jagunmolu
Bi
e
ba
n
gbo
t'omode
n
ge
′gi
ni
'gbo
Agba
lo
le
mo
'bi
to
mi
a
wo
si
B′omode
ba
rin
irin
ajo
loju
agba
O
le
ma
ba
agba
mo
ni′le
to
ba
de
o
Irin
ajo
eda
laye,
Olorun
lo
mo
Opin
irin
ajo
k'a
fi
s′adura
Opin
irin
ajo
temi
tire
ninu
aye
Oba
je
ko
san
wa
o
k'a
jagunmolu
Attention! Feel free to leave feedback.