9ice - Gbare Gbare текст песни

Текст песни Gbare Gbare - 9ice



Ah-wa-wa-wa, wa-wa, wa, wa, wa
Gbare (music)
Wa-wa-wa, wa-wa, wa, wa, wa
Áà gbàre
Gbàre-gbàre, ko gbàre ọjọ gbogbo
Ko gbà ọjọ nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, gbàre ọjọ gbogbo
ọjọ kàn ibí, ọnà àlá, ọnà àláa
'Ṣẹdá mí, èya, sọrọ, 'ṣẹdá mí, eya, sọrọ
'Ṣẹdá mí, èya, dìde, 'ṣẹdá mí, eya, dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
débẹ, débẹ, ah, pẹ
Ẹyẹlé rugbada re bi òkú, ah
Ẹyẹlé rugbada, ah
Ẹyẹlé rugbada re bi ọsa
Ẹyẹlé rugbada, ah-wa
Tótún, tòsí l'ẹyẹlé ko ore ajé wọlé
Oh-oh, rugbada, eh
Irè ajé kọ wọlé mí, kótún jáde mọ, mo rugbada
Olèlè wọnú ẹkọ, o tún jáde mọ
pe rugbada
Gbàre-gbàre ko gbàre ọjọ gbogbo
Ko gbà 'bí ọjọn kan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, gbàre ọjọ gbogbo
ọjọ kàn ibí, ọnà àlá, ọnà àláa
'Ṣẹdá mí, èya, sọrọ, 'ṣẹdá mí, eya, sọrọ
'Ṣẹdá mí, èya, dìde, 'ṣẹdá mí, eya, dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ (a-wa, wa-wa)
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
débẹ, débẹ (milẹ), ahh, pẹ
Mo ṣetàn, mo dìde gbàre te
Ọlọrun míì
Olúbùnkún, olóore te mí, kọjá Olùgbàlà, ah, ha
Irè iwájú, irè ẹhìn, irè òkè, irè ilẹ
Irè òtún, irè ósì, ko jẹ tèmí Adegbola, ọmọ Akande
Ore to ṣe Ọlọ́run, jẹ ko kalẹ
K'ọtá ṣe poṣe
Gbàre-gbàre, ko gbàre ọjọ gbogbo
Ko gbà 'bí ojo nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, gbàre ọjọ gbogbo
ọjọ kàn ibí, ọnà àlá, ọnà àláa
'Ṣẹdá mí, èya, sọrọ, 'ṣẹ̀dá mí, èya, sọrọ
'Ṣẹdá mí, èya, dìde, 'ṣẹdá mí, èya, dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
débẹ, débẹ, ahh, pẹ
(I am Izzy productions)
Ẹyẹlé rugbada re bi òkú, ah
Ẹyẹlé rugbada



Авторы: Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Альбом Afro Juju
дата релиза
17-12-2022




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.