9ice - Oloore текст песни

Текст песни Oloore - 9ice



Olóore màmá o, olóore bàbá o, olóore
Olóore
Àwọn to ń ṣáyé fún pọjù báyìí lo
Àwọn to ń ṣáyé fún pọjù bẹ ṣe ro wo-woo
Olóore bàbá o, olóore màmá o
Ore bàbá o, ore màmá o, olóore
Tẹ'nì-tẹ'nì àpá lára, igunpá níye kàn
Jọwọ, kọ so
Eh, tẹ'nì-tẹ'nì àpá lára, igunpá níye kàn
Jọwọ, kọ soo
Mọo gbójú sókè, níbo ìrànlọ́wọ́ yíò wá?
k'Adeunga, Bàbá ṣe ránwo, àá témi á kùn, lakun wo sílè ee
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Wọn Adeunga ń mí, iso lọdé
Olóore kore wá, ki ń wa gba'rẹ owó ee
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pójù báyìí lo
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pójù bẹ ṣe rọ wo-woo
Olóore bàbá o, olóore màmá o
Ore bàbá o, ore màmá, olóore
Many reason, every other day dúpẹ'
Many reason, every other day dúpẹ'
Lọwọ Toyin Kolade, Toyin Kolade
Àyà Price Kayode Kolade, Iléṣà ṣá nílé
Ìyá l'oja Odùduwà, Naija Federal
Màmá mọ kìí ée, olóore
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Toyin Kolade o
E ro wa wo lóde, e ro wo owó mọ gbà o
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pójù báyìí lo
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pójù bẹ ṣe rọ wo-woo
Olóore bàbá o, olóore màmá o
Ore bàbá o, ore màmá, olóore
Many reason, every other day dúpẹ
Many reason, every other day dúpẹ
Lọwọ àwọn olóore mí, Owó Debo
Àwọn olóore mí, Dayo Iwo
Àwọn olóore (Sina Olu MT)
Teepay, ìwọ olóore
Tiamo, Tiyabo, Tiamo, Ìwọ olóore
Omojuwa, àwọn olóore míì
(It's Bizzle on the mix)



Авторы: Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Альбом Afro Juju
дата релиза
17-12-2022




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.