9ice - Power Must Change Hands текст песни

Текст песни Power Must Change Hands - 9ice



Máà lékè wọn
Máà lékè wọn
Máà lékè wọn-
(It's Protunez on the beat)
Mo ṣí bàtà lékè odò o
Ẹjá arọ ń bẹ nísàlẹ odò o
f'ẹjá bọ'rí, gbémilékè wọn
Ìgbàgbọ mi lára
Gbogbo àgbára po padà, ahh
Mo lékè wọn
Now, I'm grinding, my enemies are crawling
Some dey beside, but never see me coming
My train is nonstop, don't ever try to cross me
Ah, mo lékè wọn
I know, power must change hands right now
They know, ẹlẹmi lo last right now
B'okun o rú, b'ọsa o
Ìwọ lékè wọn
B'okun o rú, b'ọsa o ru
Àwa lékè wọn
Ọmọ to ń pá'dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè shana
Ọmọ to ń pá'dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lọ lolè ṣ'ana
Mo kotá, mo kòpée, ọtá ń jẹ
ò gbọdọ fọ'hùn
Ọmọ ń pá'wó, tọ ń ṣiṣẹ́
Ò gbọdọ májẹ ìgbádùn
Ojú ẹnì lá, dandan arí ìyọnu
Áìfaila ọjọ, t'ọjọ bálá, máa làá
Now, I'm grinding, my enemies are crawling
Some dey beside, but never see me coming
My train is nonstop, don't ever try to cross me
Ahh, mo lékè wọn
I know (má lékè wọn), power must change hands right now (ìyá wọn, bàbá wọn)
They know, ẹlẹmi lo last right now
B'okun o (b'owó ru), b'ọsa o (b'owó ru)
Ìwọ lékè wọn lékè wọn)
B'okun o rú, b'ọsa o
Àwa lékè wọn (eh-eh-eh-ehh)
Ọmọ ń pá'dán (ọmọ), idán gan-gan idán (ko pá'dán lọ)
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè shana
Ọmọ to ń pá'dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lọ lolè ṣ'anaa



Авторы: Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Альбом Afro Juju
дата релиза
17-12-2022




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.