9ice - Olorun Loni Kori Be E текст песни

Текст песни Olorun Loni Kori Be E - 9ice



(Xtra Pro)
Ahh, Ọlọ́run lónìí bẹẹ
Ọgbọn inú lo sọ mi dáwo dumatẹ
Òkè torí gágára àṣẹ Rẹ, àdipẹtẹlẹ
Ìṣòro ńdi lọwọ, gbọrọ Olùwà, mi níde
Òkè torí gágára àṣẹ Rẹ, àdipẹtẹlẹ
Ìṣòro ńdi lọwọ, gbọrọ Olùwà, mi níde
Bàbá gbọ, O mí,
Májẹ k'àyé fọwọ bo'ràwọ̀
Bàbá gbọ, O ríi,
Májẹ k'àyé fọwọ bo'ràwọ̀
lọ sọ Ọlọrun? (Tá lọ sọ pé?)
Ènìyàn lo sọ kọ Ọlọrun
lọ sọ Ọlọrun? (Táa, lọ, lo sọ pé?)
Ènìyàn lo sọ kọ Ọlọrun
Ahh, Ọlọ́run lónìí bẹẹ (kò bẹẹ)
Ọgbọn inú lo sọ mi dáwo dumatẹ
Òkè torí gágára àṣẹ Rẹ, àdipẹtẹlẹ (òkè, eh-eh)
Ìṣòro ńdi lọwọ, gbọrọ Olùwà, mi nídẹ (gbémilékè)
Òkè torí gágára àṣẹ Rẹ, àdipẹtẹlẹ
Ìṣòro ń di lọwọ, gbọrọ Olùwà, mi níde
Bẹ fẹ, bẹẹ kọ, gbọ ohùn ẹnu tọ ń geere
gùn ìyán sínú odo, k'oto
Máà sebẹ sínú epò ẹpá, ẹni máyo, àáyo
Ọrọ ẹmi at'Ọlọrun láyé mí, kọ ṣe dásí
Láti ìpẹpẹ Lo ń ṣe bẹbẹ, kọ ṣe dásí
Èmí máà
Òkè torí gágára àṣẹ Rẹ, àdipẹtẹlẹ (máa Ẹ, máa Ẹ, Ọlọrun mí)
Ìṣòro (Xtra Pro) ńdi lọwọ, gbọrọ Olùwà, mi níde
(It's Bizzle on the mix)



Авторы: Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Альбом Afro Juju
дата релиза
17-12-2022




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.