Текст песни Adena Ike - King Sunny Ade
Oro
gbogbo
lori
owo,
yes
otito
ni
A'i
si
owo
baba
ijaya,
yes
otito
ni
A
l'owo
lowo
baba
ifokanbale,
yes
otito
ni
A
l'owo
lowo
baba
afojudi,
yes
otito
ni
Bi
a
ba
l'owo
lowo
la
n
da'moran
nla,
yes
otito
ni
Adenaike
currency
controller,
yes
otito
ni
Oyinbo
ile
owo
ni,
oyinbo
ile
owo
o
Adenaike,
oyinbo
ile
owo
o
Gboyega,
oyinbo
ile
owo
o
Baba
Gbenga,
oyinbo
ile
owo
o
Oko
Funke,
oyinbo
ile
owo
o
Ijebu
Omu
maa
ba
lo,
oyinbo
ile
owo
o
Toba
digba
owuro,
ka
fi
gbele
pa'wo
Toba
digba
owuro
sir,
ka
fi
gbele
pa'wo
Ka
na'wo
funfun,
ka
na'wo
pupa,
kawa
da
lari
bora
Igba
laye
ooo
N
ba
lowo
n
ba
yo,
oyinbo
ile
owo
o
O
tun
gbe
tuntun
de,
ololu
Currency
controller
mi,
ololu
Gboyega
Adenaike,
ololu
Olowo
gboye
meji
po,
ololu
Ma
ya'na
ma
lo
sodo
padi
mi
Nurudeeni
omo
Animasahun
Omo
Animasahun,
omo
Animasahun
Omo
Animasahun,
omo
Animasahun
Nurudeen
omo
Animasahun
The
barrister
omo
Animasahun
Managing
director,
omo
Animasahun
Oko
alhaja,
omo
Animasahun
Nurudeen,
omo
Animasahun
Ma
fi'ya
je
o,
oba
oluwa
ma
fi'ya
je
o
Ma
fi'ya
je
o,
oba
oluwa
ma
fi'ya
je
o
Oluwa
ma
fi'ya
je
omo
Animasahun,
ma
fi'ya
je
o
Ma
fi'ya
je
o,
oba
oluwa
ma
fi'ya
je
o
Ma
fi'ya
je,
oba
oluwa
ma
fi'ya
je
o
Oluwa
ma
fi'ya
je
omo
Animasahun,
ma
fi'ya
je
o
Nurudeen
omo
toba
be,
ma
fi'ya
je
o
Oko
alhaja
mi,
ma
fi'ya
je
o
Oluwa
ma
fi'ya
je
omo
Animasahun,
ma
fi'ya
je
o
Odi
ile
Ayo
Sasanya
mi,
oyinbo
oni
sowo
Ayo
Sasanya,
oyinbo
oni
sowo
Ayo
Sasanya,
oyinbo
oni
sowo
Ayo
Sasanya,
oba
je
o
gbadun
laye
Ko
rere
oja
je
Ko
sowo
ko
jere,
ko
rere
oja
je
Ki'wo
ma
padanu
nile
aye
re
Ko
olori
buruku
ko
ma
maa
koba
e
Amin
o
ase
o,
Ayo
Sasanya
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.