King Sunny Ade - Alhaji Chief Larewaju Kazeem текст песни

Текст песни Alhaji Chief Larewaju Kazeem - King Sunny Ade



Larewaju omo ara iriwu
Chief Bobagunwa mi omo ara iriwu
Asale jeje bi e ni ti o robirin ri
Omo asale jeje bi e ni ti o robinrin ri
Bi ogun bi ogbon aya won nbe nile
Bi ogun bi ogbon aya won nbe nile o
A baya nile titi iji agbo o je arigbabuwo
Ore Alihaji Agboola Alausa
Won jo nrin po won o maa tanrawonje
Ore executive director shofa
Iyen ni chief otun Balogun Ijebuland
Alhaji Okunola Shote ti gbogbo wa mọsi
Lovely lovely lovely baba ni baba
Awo Alhaji M A Sule
Awo Alhaji Shola Subaru mi
Olarewaju tiwa ni o tiwa ni
Bami toju aburo re
Demola Kazeem executive director
Ibukun orisun iye baba ni baba
Director mot mokson
Olola aare agadagudu
Agada agada sociable agada
Aare Larewaju agada agada agada
Aare agadagudu Bobagunwa agada agada
Olarewaju agada aare agadagudu agada
Olarewaju o maa ni te lawujo gbogbo olowo pata
Omo eriwo omo eriwo
Ko maa ni je kilu agan o bale
Larewaju o ni te laye
Olarewaju o maa ni te lawujo olowo o
Omo eriwo omo eriwo
Ko maa ni je kilu agan o bale
Larewaju o ni te laye
Larewaju ko le kan agbayanu ni
Chief Bobagunwa ko le kan agbayanu ni
A nise be ti latigi nbe
Oke arafa nbe
Be ti latigi nbe
Oke arafa nbe
Alujanna aye nbe lodo a sanyi o
Alujanna aye nbe lodo a sanyi o
Bobagunwa castle ni Jebuigbo
Oluwa lofohun rere da sociable lola
O di terere terere terere
Maa lo ki onitemi o baba ni baba
Alhaji chief otun balogun ana osi balogun
Keshin kese bo de nu baba won
Bi o dokan won
Keshin kese
Asote ma mo omo Tewogbola
Katako eshin kii je shin o subu subu
Kii je shin o subu
Iru eshin kii we meshin lorun
Iya eni baba eni kii jo ju oti ni
Chief Otun Balogun gbogbo Ijebu-land
Olowo ori oko Alhaja Kudiratu Balogun
Olowo ori oko Alhaja Afolashade
Baba Mosunmola, baba Olalekan
Baba Babatunde, baba Omotayo,baba Olukorede
Chief Otun Balogun ana osi Balogun
Keshin kese bo de nu baba won
Bi o dokan won
Keshin kese
Asote maa mo omo Tewogbola
Katako eshin kii je shin o subu
Iru eshin kii we meshin lorun
Iya eni baba eni kii jo ju oti ni
Alhaji chief Baba nile baba maa ni lode
Éyinbo elepo pupa
Gbaponbelesu lesu lesu lesu
Obenbelesu
Omo tori ogun wa



Авторы: King Sunny Adé


King Sunny Ade - Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
Альбом Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
дата релиза
27-11-1999




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.