King Sunny Ade - E Yi Ga текст песни

Текст песни E Yi Ga - King Sunny Ade



Adeniyi lo nki yin o
Awi t′ana da, a gbe tuntun le
Eyi ga (ah), oga lagaju, eyi ga
Awi t'ana danu, a gbe tuntun le
Eyi ga, oga lagaju, eyi ga
E ma gbo
Iye ni ye eyele, iye ni ye eyele o
Irubo ni raga ba l′orun
Ayo mi k'ale o jare ni'le aye
A ye mi l′oke okun
A ye mi n′ile Naija
A ye mi l'ode agbaye
Ati ile ti mo n gbe
A ye mi l′oke okun
A ye mi n'ile Naija
A ye mi l′ode agbaye
Ati ile ti mo n gbe
Ati inu ile ti mo n gbe
(Ati inu ile ti mo n gbe)
Ati inu ebi ti mo ni
A ye mi l'oke okun
A ye mi n′ile Naija
A ye mi l'ode agbaye
Ati inu ile ti mo n gbe
Agbe t'ana da, a gbe tuntun le
Eyi ga, oga lagaju, eyi ga
African beat, tutntun la gbe de
Eyi ga, oga lagaju, eyi ga
Iye ni ye eyele
Irubo ni raga ba l′orun
Eyi ga




King Sunny Ade - Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
Альбом Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
дата релиза
27-11-1999




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.