King Sunny Ade - Elegede Njaiye текст песни

Текст песни Elegede Njaiye - King Sunny Ade



Bami wa solution si oro aye mi
Bami wa solution si oro aye mi
Mase je kope ju
Mase je kope ju
Ke mi le wa sope
Baba onibu ore
Edumare onibu ore
Baba loke mon ke pe o
Bami wa solution soro mi
Bami wa solution sile aye mi
Gba koso aye mi o baba mimo
Eyi oku funmi nile aye mi
Jowo dakun lo mi fun ogo re o baba wa
Bami wa solution si oro aye mi
Bami wa solution si oro aye mi
Mase je kope ju
Mase je kope ju
Ke mi le wa sope
Elegede njaye ori e ninu oko
Ogbale lo repete
Ila iroko re e oba ni nile ikan
Igbin ilu koko to fimo nu egan
Won o lafiwe e rora
Ogbo a gidigbi gbogbo ara lo fin sowo
Alade mi maa mikan
Ohun gbogbo ni sepe
Oro le so e o puro
Oro le so e o puro o jare
Oro le so e o puro
Oro le so e o puro o
Elegede njaye ori e ninu oko
Ogbale lo repete te te te
Ila iroko te ri yen oba ni nile ikan o jàre
Maa maa wipe
Elegede njaye ori e ninu oko
Ogbale lo repete
Ila iroko re e oba ni nile ikan
Igbin ilu koko to fimo ti nu egan
Won o lafiwe e rọra
Ogbo a girigbi gbogbo ara lo fin sowo
Alade mi maa mi kan
Ohun gbogbo ni sepe
Ohun gbogbo ni sepe
Ohun gbogbo ni sepe
Ohun gbogbo ni sepe
Ohun gbogbo ni sepe
Ohun gbogbo ni sepe
Ohun gbogbo ni sepe
Elegede njaye ori e ninu oko
Ogbale lo repete
Ila iroko re oba ni nile ikan
Igbin ilu koko to fimo ti nu egan
Won o lafiwe e rora
Ogbo a gidigbi gbogbo ara lo fin sowo
Alade mi maa mi kan
Ohun gbogbo ni sepe
Ina ti e da kii se fun wa rara
Ekeye mogbo
Efina soko yi ka
Akere wo do elefe fi na le jade
Ohun ti o le bo si
Ohun le nra wo le
Elewa titi Oluwa o funyin se
Ayanmo o gbogun
Ori le le jo
Ina ti e da kii se fun wa rara
Ekeye mogbo
Efina soko yi ka
Akere wo do elefe fi na le jade
Ohun o le bo Si
Ohun le nra wole
Elewa titi Oluwa o fun yin se
Ayanmo o gbogun
Ori le le jo
Ayanmo o gbogun
Ori le le jo
Iyen ti daju
Ori le le jo
Ayanmo o gbogun
Ori le le jo
Iyen ti yemi ye ke
Ori le le jo
Sunny Ade maa nki yin o
Sunny Ade maa nki yin o
Onishola maa nki yin o
Onishola maa nki yin o
Oni e lowo e bimo
Oni e lowo e bimo
Oni e sowo e jere
Oni e sowo e jere
Adeniyi lo nki yin o
Agbe tana da nu
Atugbe tuntun de
Eyi ga ha o ga lagaju e yi ga
Agbe tana da nu
Atugbe tuntun de e
Eyi ga o ga lagaju e yi ga
Ema gbo yi ye ni ye yele
Yi ye ni ye yele o
Ri ro ni ra daba lorun
Ayewa kale o jare
Nile aiye mi
Ayemi loke okun
Ayemi nile Naija
Ayemi mi lode agbaye
Ati nu ile ti mo ngbe
Ayemi loke okun
Ayemi nile Naija
Ayemi lode agbaye
Ati nu ile ti mo ngbe
Ati nu ile ti mo ngbe
Ati nu ile ti mo ngbe
Ati nu ebi ti mo ni
Ati nu ile ti mo ngbe
Ayemi loke okun
Ayemi nile Naija
Ayemi lode agbaye
Ati nu ile ti mo ngbe
Agbe tana da nu
Atungbe tuntun de
Eyi ga o ga lagaju eyi ga
Afrikan beat tuntun lagbede
Eyi ga o ga lagaju eyi ga
Yi ye ni ye yele
Riro ni ro adaba lorun
Eyi ga o ga lagaju eyiga
Oga lagaju eyi ga



Авторы: King Sunny Adé


King Sunny Ade - Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
Альбом Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
дата релиза
27-11-1999




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.