King Sunny Ade - E Ba Mi Dupe текст песни

Текст песни E Ba Mi Dupe - King Sunny Ade



Mo de o baba, mo wa ṣọpẹ, ore nla
Baba ti gba
Awọn ọmọ rẹ lo timi ninu
E ba mi dupẹ f'oluwa to ran mi lọwọ
Baba gba mi lọwọ ìṣòro
Ka to ni jẹ
Emi mo fi fún oluwa
Fún ọrẹ rẹ
Ọpẹ mi pẹlẹ si mi o tumi ninu
Mo ti majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a
Mo wa ba olore ọfẹ
To ṣe ye bi, to muṣẹ wa
Mo de o baba, mo wa ṣọpẹ, ore nla
Baba ti gba
Awọn ọmọ rẹ lo timi ninu
E ba mi dupẹ f'oluwa to ran mi lọwọ
Baba gba mi lọwọ ìṣòro
Ka to ni jẹ
Emi mo fi fún oluwa
Fún ọrẹ rẹ
Ọpẹ mi pẹlẹ si mi o tumi ninu
'Tori, mo ti majẹmu o e, mo ti majẹmu o a
Mo wa ba olore ọfẹ
To ṣe ye bi, to muṣẹ wa
Ore ọfẹ lo damisi, mo ma yẹn náà
Ọlọlá lo ji ọta mi o
Emi a jo
Iku folọ amuse gbé o eyitope
Baba wa leti ọdọ mi to n wo mi lọwọ
ba mi jo ẹyin ara mi
Ile ayé, k' ọpẹ mi, kòtò ọwọ' laan tọrọ
Mo ti majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a
Mo wa ba olore ọfẹ
To ṣe ye bi, to muṣẹ wa



Авторы: King Sunny Adé


King Sunny Ade - Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
Альбом Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide
дата релиза
27-11-1999




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.