9ice - Murebo текст песни

Текст песни Murebo - 9ice



(It's Protunez on the beat)
Àjò to re o, murebọ o
Àjò to re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ, ọ-ọ-o
Owó wọlé o, ire dé, ọlá wọlé o, ọmọ
Ẹlẹgbẹ́, mo ní, "Ẹ jẹ à f'ẹran kọ"
beer ṣeré pá, beer ṣeré
Lager beer, ṣeré pá, lábẹ wire, ṣeré
Don't be a stupid man o
Life is full of ups and down
If you dey enjoy, brother, appreciate your grace
Àwọn ń bẹ nílé, jẹ kàn t'arà rẹ gain
Time to enjoy, brother, make you no dey play
Be'wù b'ẹ n 'lé, f'olè ṣọ gate
Stop playing!
Àjò to re o, murebọ o
Àjò to re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ o
Àjò mo rẹ o, murebọ, ọ-ọ-o
Owó wọlé o, ire dé, olá wọlé o, ọmọ
Ẹlẹgbẹ́, mo ní, "Ẹ jẹ à f'ẹran kọ"
beer ṣeré pá, beer ṣeré
Lager beer, ṣeré pá, lábẹ wire, ṣeré
Òbí, mù'ré
yín f'Oluwa, àṣírí yìn lọ ń bẹrẹ ń bo
Them be dey check, but them dey collect
Who dey checker? Dem go collect
Dem dey spend náírà, we dey spend dollar
Bo ṣe cefa, a sọ paper
Ògò Olúwa ní, don't take it personal
I love my beer, odún lẹnu proper
Stop playing!
Àjò to re o, murebọ o
Àjò to re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ, ọ-ọ-o
Owó wọlé o, irẹ dé, olá wọlé o, ọmọ
Ẹlẹgbẹ́, mo ní, "Ẹ jẹ à f'ẹran kọ"
beer ṣeré pá, beer ṣeré
Lager beer, ṣeré pá, lábẹ wire, ṣeré
(It's Bizzle on the mix)



Авторы: Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Альбом Afro Juju
дата релиза
17-12-2022




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.