9ice - Oloore текст песни

Текст песни Oloore - 9ice



Olóore màmá o, olóore bàbá o, olóore
Olóore
Àwọn to ń ṣáyé fún pọjù báyìí lọ
Àwọn to ń ṣáyé fún pọjù bẹ ṣe ro, wo-woo
Olóore bàbá o, olóore màmá o
Ore bàbá o, ore màmá o, olóore
Tẹnì-tẹnì àpá lára, igunpá níye kàn
Jọwọ, kọ sọ
Eh, tẹnì-tẹnì àpá lára, igunpá níye kàn
Jọwọ, kọ sọọ́
Mo gbójú sókè, níbo ìrànlọ́wọ́ ò wá?
k'Adeunga, Bàbá ṣe ránwọ, àá témi á kùn, lakun wọ sílẹ, ee
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Wọn Adeunga ń mí, ìṣó lodé
Olóore kore wá, ki ń wa gba're owó ee
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pọju báyìí lọ
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pọjù bẹ ṣe ro, wo-woo
Olóore bàbá o, olóore màmá o
Ore bàbá o, ore màmá, olóore
Many reason, every other day dúpẹ
Many reason, every other day dúpẹ
Lọwọ Toyin Kọlade, Toyin Kọlade
Àyà Price Káyọ̀dé Kọlade, Iléṣà ṣá nílé
Ìyá l'Ọjà Odùduwà, Naija Federal
Màmá, mo kìí ẹ, ẹ-ẹ, olóore
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Ilé mo wa tọ jí, tọ
Toyin Kọlade o
E ro wa wo lóde, e ro wo owó mo gbà o
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pọjù báyìí lọ
Àwọn tọ ń ṣáyé fún pọjù bẹ ṣe ro, wo-woo
Olóore bàbá o, olóore màmá o
Ore bàbá o, ore màmá, olóore
Many reason, every other day dúpẹ
Many reason, every other day dúpẹ
Lọwọ àwọn olóore mí, Owó Debọ
Àwọn olóore, Dayọ Iwo
Àwọn olóore (Ṣina Olu MT)
Teepay, ìwọ olóore
Tiamo, Tiyabo, Tiamo, iwọ olóore
Ọmọjuwa, àwọn olóore míì
(It's Bizzle on the mix)



Авторы: Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Альбом Afro Juju
дата релиза
17-12-2022




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.